Ojú ìwé 2
Àwọn Irú Ọ̀wọ́ Tí A Wu Léwu Èrèdí Ìdàníyàn? 3-10
Lọ́dọọdún, àwọn irú ọ̀wọ́ ohun alààyè púpọ̀ sí i ń kú àkúrun. Kí ni èyí túmọ̀ sí fún wa?
Ó Ha Yẹ Kí O Bẹ̀rù Òkú Bí? 18
Ibo ni àwọn òkú wà? Ǹjẹ́ wọ́n lè pa alààyè lára?
Músítádì—Kókó Ọ̀rọ̀ Afàfẹ́mọ́ra Gbígbóná Janjan 22
Músítádì ti lókìkí láti ọjọ́ gbọọrọ wá. Báwo ni a ṣe ń mú un jáde?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fọ́tò ẹ̀yìn ìwé: Pẹ̀lú ìyọ̀ọ̀da onínúure Madrid Zoo, Madrid, Spain