Ojú ìwé 2
Ìwọra Báwo Ló Ṣe Kàn Wá? 3-10
Ìwọra aráyé ń pa àwọn búrùjí ilẹ̀ ayé run. Ó ń kó àwọn aláìní nífà, ó sì ń fi kún ọrọ̀ àwọn ọlọ́rọ̀. Báwo ni ìwọ ṣe lè máa wà nìṣó nínú ayé tí ìwọra ti gba ipò iwájú? Ìwọra yóò ha kúrò nílẹ̀ láé bí?
Orin, Oògùn Líle, àti Ìmutípara Ló Jàrábà Ìgbésí Ayé Mi Tẹ́lẹ̀ Rí 11
Ọmọ Íńdíà ti ẹ̀yà Chippewa kan tí ó ti ogun Vietnam bọ̀ ṣàlàyé bí ó ṣe yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà.
Ilẹ̀ Ayé Yóò Ha Jóná Lúúlúú Bí? 26
Láti ọ̀pọ̀ ọ̀rúndún wá ni ìsìn púpọ̀ ti ń fi kọ́ni pé ilẹ̀ ayé yóò jóná lúúlúú. Kí ni ojú ìwòye Bíbélì?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ilẹ̀ ayé lójú ìwé 2 sí 4, 6, 9, àti 26: A gbé e karí fọ́tò NASA