Ojú ìwé 2
Ìṣòro Omi Wàhálà Tó Kárí Ayé 3-11
Èé ṣe tí ìṣòro fi wà? Kí ni ojútùú rẹ̀?
Via Egnatia—Òpópó Kan Tó Ṣèrànwọ́ fún Ìmúgbòòrò 16
Òpópó kan tí a ṣe fún ìmúgbòòrò iṣẹ́ ológun ní Róòmù tún mú àwọn àǹfààní tẹ̀mí wá fún àwọn ará Makedóníà.
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Rọ́ṣíà 22
Kà nípa bí ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn kan tí ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Rọ́ṣíà ṣe ṣàtúnṣe àwọn èrò òdì nípa Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà.