Ojú ìwé 2
Òṣì Yóò Dópin Láìpẹ́ 3-11
Àkókò tí a óò mú òṣì kúrò lórí ilẹ̀ ayé títí láé ti dé tán. Lọ́nà wo?
Ǹjẹ́ Jíjẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Wà Láìgbéyàwó Pọndandan fún Kristẹni Òjíṣẹ́ Bí? 16
Kí ni ojú ìwòye Bíbélì?
Èyí Tí Mo Yàn Nínú Bàbá Méjì 18
Kí ló sún ọ̀dọ́kùnrin kan ṣe yíyàn tó ṣòro yìí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Life