Ojú ìwé 2
Ǹjẹ́ Àkókò Ti Tó Láti Gbàgbé Ọ̀rúndún Oníwà Ìkà? 3-11
Ìwà ìkà ti gbẹ̀mí àràádọ́ta ọ̀kẹ́ ènìyàn. Ta ló lè mú kí ó dájú pé kò tún ní ṣẹlẹ̀ mọ́?
Báwo Ni Ìsìn Ṣe Ń Jẹ Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́kàn Tó? 12
Kí ni èrò àwọn ọ̀dọ́ nípa ìsìn lóde òní?
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . N Kò Ṣe Lè Pọkàn Pọ̀? 22
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ọmọbìnrin ará Faransé kan tó fara pa: Fọ́tò U.S. Navy
Òkú àwọn olùwá-ibi-ìsádi ará Rwanda: UN PHOTO 186809/J. Isaac
Encyclopædia Britannica/Ìtẹ̀jáde Kọkànlá (1911)