Ojú ìwé 2
Ìrètí Wo Ló Wà fún Àwọn Èwe Òde Òní? 3-10
Kí ló dé tí ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ ń kú láìtọ́jọ́? Kí ló sì fà á tí wọ́n fi ń pa ara wọn lọ́pọ̀ ìgbà? Ǹjẹ́ ojútùú kankan wà fún ọ̀ràn ìbànújẹ́ yìí?
Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀—Àwọn Ènìyàn Ń mọ Àǹfààní Rẹ̀ 18
Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ níbi gbogbo ni àwọn dókítà tí ń ṣagbátẹrù iṣẹ́ abẹ láìlo ẹ̀jẹ̀. Wá mọ ìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀.
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí A Máa Di Ẹrù Ẹ̀ṣẹ̀ Wa Lé Sátánì Lórí? 24
Ǹjẹ́ Sátánì ló lẹ̀bi àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa? Dé àyè wo ni àwa fúnra wa fi ní láti jíhìn ohun tí a bá ṣe?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Erich Lessing/Art Resource, NY