Ojú ìwé 2
Jésù—Báwo Ló Ṣe Rí Gan-an? Kí Ló Jẹ́ Nísinsìnyí? 3-11
Ta tilẹ̀ ni Jésù Kristi gan-an? Báwo ló ṣe rí? Ipa wo ló ń kó nísinsìnyí nínú ète Ọlọ́run?
“Àwa Jáwọ́ Ńbẹ̀—Ìwọ Náà Lè Ṣe Bẹ́ẹ̀!” 19
Kí ló sún àwọn amusìgá wọ̀nyí jáwọ́ nínú àṣà náà?
Ìjábá Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Yóò Ha Pa Ayé Wa Run Bí? 22
Kí ni Bíbélì sọ?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Láti inú ìwé Wider die Pfaffenherrschaft
Cathedral of Apt, France
Àwòrán ọwọ́ ẹ̀yìn èèpo ìwé: The Last Supper/The Doré Bible Illustrations/Dover Publications