Atọ́ka fún Ìdìpọ̀ Kọkàndínlọ́gọ́rin ti JÍ!
ÀJỌṢEPỌ̀ Ẹ̀DÁ
Kò Kólòlò Mọ́! 10/8
Nígbà Tí Àwọn Ọmọ Bá Fi Ilé Sílẹ̀, 1/22
ÀWỌN ÀLÁMỌ̀RÍ ÀTI IPÒ AYÉ
A Ń Yí Ojú Ọjọ́ Wa Padà Bí? 5/22
Àwọn Igbó Kìjikìji, 5/8
Àwọn Ìpáǹle Ọ̀dọ́langba, 11/8
Àwọn Obìnrin, 4/8
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ìta, 4/22
Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn, 12/8
Fàyàwọ́ (Yúróòpù), 10/8
Gbogbo Ènìyàn Yóò Nífẹ̀ẹ́ Ara Wọn Bí? 11/8
Ìdí Tí A Kì Í Fi Í Rí Ìràwọ̀, 4/22
Ìháragàgà fún Ìsọfúnni, 1/8
Ìpolówó Ọjà, 9/8
Ipò Òṣì, 6/8
Ìrètí Tó Wà fún Àwọn Èwe Òde Òní, 9/8
Ìwà Ọ̀daràn, 2/22
Ọ̀rúndún Oníwà Ìkà, 8/8
Pípa Ara Ẹni—Ìṣòro Wíwọ́pọ̀ Láàárín Àwọn Ọ̀dọ́, 9/8
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Àwọn Àpéjọpọ̀ “Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Tí Ọlọ́run Fẹ́,” 6/8
Àwọn Onígboyà Lójú Ewu Nazi, 7/8
Ẹ̀bẹ̀ Òṣìṣẹ́ Amúdàájọ́ṣẹ, 6/22
Ìgbìmọ̀ Amójútó Ọ̀ràn Ìdájọ́ Ilẹ̀ Rọ́ṣíà Dá Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Láre, 12/8
Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Ṣàtúnṣe Àìtọ́ Kan, 1/8
Ilé Iṣẹ́ Agbéròyìnjáde Ilẹ̀ Rọ́ṣíà Gbóríyìn, 2/22
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN
A Ń Wu Òdòdó Orchid Léwu Bí? 10/8
Àwọn Èrò Òdì Nípa Ejò, 11/8
Àwọn Igbó Kìjikìji, 5/8
Àwọn Ìnàkí Orí Òkè, 1/22
Àwọn Ohun Iyebíye Ojú Òfuurufú Áfíríkà (àwọn ẹyẹ àrọ̀nì), 8/8
Àwọn Oyin Bá Adìyẹ Pamọ! 5/22
Àwọn Rhino Tí Kò Lóbìí ní Kẹ́ńyà, 8/8
Dóńgóyárò (igi), 2/22
Ewéko Yucca Aláradídán, 1/22
Eyín Erin (iye erin tí a ń pàdánù), 3/22
Ẹranko Puma, 4/22
Ẹyẹ Tí Ó Ní Ìpéǹpéjú, 1/8
Ìpadàbọ̀ Ẹyẹ Funfun Títóbi Náà (albatross), 5/22
Òbéjé Irrawaddy, 4/8
Wíwo Ẹyẹ, 7/8
Ylang-Ylang (igi), 6/22
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Àwọn Àwòkọ́ṣe, 5/22
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Pọkàn Pọ̀? 10/8
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sọ Òtítọ́ Di Tèmi? 11/8
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Wá Owó? 9/8
Bí Àwọn Òbí Mi Kò Bá Fara Mọ́ Ìgbéyàwó Mi Ńkọ́? 1/22
Bí Kò Bá Nífẹ̀ẹ́ Mi Bí Mo Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Rẹ̀ Ńkọ́? 6/22
Fífi Ẹ̀yà Ẹni Yangàn, 2/22
Jíjẹ́ Kí Ọ̀rẹ́ Gba Àkókò Ẹni, 4/22
Mo Ṣe Ní Láti Wà Láìní Òbí? 12/8
N Kò Ṣe Lè Pọkàn Pọ̀? 8/8
Títúbọ̀ Ṣe Dáradára Nílé Ẹ̀kọ́, 3/22
ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN
Àìsàn Iṣan Òun Ẹran Ara Ríro, 6/8
Àrùn AIDS, 11/8
Àrùn Ẹ̀gbà, 2/8
Ibà Dengue—Ibà Tí Ń Ṣe Ẹni Tí Ẹ̀fọn Bá Jẹ, 8/8
Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Abẹ Ìṣiṣẹ́ Abẹ, 2/22
Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀, 9/8
Iṣẹ́ Ìṣàtúntò Eyín, 4/8
Jáwọ́ Nínú Sìgá Mímu, 12/8
Kíkápá Àìfararọ, 3/22
Kíkọ̀ Láti Gbẹ̀jẹ̀, 10/8
Kò Kólòlò Mọ́! 10/8
Lílo Oògùn Láìkọ́kọ́rí-Dókítà, 7/8
O Ha Máa Ń Jẹ Eyín Rẹ Bí? 3/22
Omi àti Ìlera Rẹ, 3/22
Ọ̀rẹ́ Rẹ́rùnrẹ́rùn (Ikọ́ Ẹ̀gbẹ àti Fáírọ́ọ̀sì HIV), 7/8
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN
Adágún Victoria (Áfíríkà), 12/8
A Fi Orúkọ Ọlọ́run Ṣe Àwọn Ilé Lọ́ṣọ̀ọ́ ní Czech, 4/22
Àràmàǹdà Àwọn Àtòpọ̀ Òkúta (Yúróòpù), 5/8
Aṣọ Chitenge Tó Wúlò Lọ́nà Púpọ̀ (Áfíríkà), 1/22
Àwọn Ará Inca, 1/8
Àwọn Erékùṣù Tí Ń Kóra Jọ (Hawaii), 5/22
Àwọn Èṣù Oníjó ní Yare (Venezuela), 2/8
Àwọn Kristẹni àti Ètò Kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́ (Íńdíà), 3/8
Àwọn Òkè Ńlá ti Òṣùpá (Kẹ́ńyà), 2/8
Calcutta, 7/8
Georgia—Ogún Àtayébáyé, 1/22
Gbígbẹ́ Ọnà Ọ̀pá Ìtẹ̀lẹ̀ (Britain), 3/22
Híhun Súẹ́tà—Ní Patagonia, 5/8
Irúgbìn Amaranth—Oúnjẹ Láti Ọ̀dọ̀ Àwọn Aztec, 5/22
Ìsìn ní Poland Òde Òní, 10/8
Kí Ló Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Apache? 3/8
Ọ̀nà Márùn-ún Láti Mú Kí Ìgbésí Ayé Sunwọ̀n sí I (àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ń gòkè àgbà), 5/22
Ylang-Ylang—Láti Erékùṣù Olóòórùn-Dídùn (Mayotte), 6/22
ÌSÌN
Àdúrà, 6/8
A Fi Orúkọ Ọlọ́run Ṣe Àwọn Ilé Lọ́ṣọ̀ọ́ ní Czech, 4/22
“Àlàfo Àárín Àwùjọ Àlùfáà àti Àwọn Ọmọ Ìjọ Ń Fẹ̀ Sí I,” 1/8
Àwọn Irin Iṣẹ́ Ìdánilóró Tí Kò Ṣeé Finú Wòye, 4/8
Àwọn Ìtumọ̀ Bíbélì Ìjímìjí, 5/8
Àwọn Kristẹni àti Ètò Kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́, 3/8
Ibojì Kristi ní Japan Kẹ̀? 4/8
Ìparadà—Ǹjẹ́ Rírí Ni Ẹ̀rí fún Wíwà?, 6/8
Ìpàtẹ Ọjà Ìsìn (Ítálì), 3/8
Ipa Tí Ìjọ Kátólíìkì Kó Nínú Ìpakúpa Náà, 11/8
Jésù—Nígbà Yẹn Lọ́hùn-ún àti Nísinsìnyí, 12/8
Ǹjẹ́ Ìsìn Ń Jẹ Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́kàn? 8/8
Poland, 10/8
Wọ́n Ṣí Ibi Àkójọ Ìwé Àṣírí Fáráyé Wọ̀ (Ìwádìí Láti Gbógunti Àdámọ̀), 12/8
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Bí Ìdílé Mi Ṣe Dúró Ṣinṣin Ti Ọlọ́run Sún Mi Ṣiṣẹ́ (H. Henschel), 2/22
Bí Mo Ṣe Kojú Ìkólòlò (S. Sievers), 1/22
Èyí Tí Mo Yàn Nínú Bàbá Méjì, 6/8
Ìfẹ́ Mi fún Ilẹ̀ Ayé Yóò Ṣẹ Títí Láé (D. Connelly), 9/8
Ìlérí Tí Mo Múra Tán Láti Mú Ṣẹ (M. Tsiboulski), 6/22
Ìrìn Àjò Láti Inú Ìwàláàyè àti Ikú ní Cambodia (W. Meas), 5/8
Ìsapá Wa Lórí Ẹ̀tọ́ Láti Wàásù (G. Marsh), 4/22
Rírí Ìtùnú Nínú “Àfonífojì Ibú Òjìji” (B. Schweizer), 4/8
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Ha Wà Ní Tòótọ́ Bí? 4/8
Ẹ̀jẹ́ Àìgbéyàwó Pọndandan fún Àwọn Òjíṣẹ́ Bí? 6/8
Ẹ̀kọ́ Ìwé, 3/8
Ìjábá Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Yóò Pa Ayé Wa Run Bí? 12/8
Ìjẹ́pàtàkì Dídáwà, 10/8
Ìṣọ̀kan Kristẹni Fàyè Gba Jíjẹ́ Onírúurú Bí? 2/8
Ìwà Ìkà sí Àwọn Ẹranko, 11/8
Kí A Bẹ̀rù Ọlọ́run Ìfẹ́ Kẹ̀? 1/8
Ó Ha Yẹ Ká Máa Di Ẹ̀ṣẹ̀ Wa Lé Sátànì Lórí Bí? 9/8
Ọdún 2000, 5/8
Ọ̀nà Ìwọṣọ àti Ìmúra, 8/8
Títage, 7/8
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
A Sá fún Bọ́ǹbù—50 Ọdún Lẹ́yìn Náà! 3/8
Àwọn Abójútó Ilé Iná Atọ́nà Ọkọ̀ Òkun, 2/22
Àwọn Afárá, 11/8
Àwọn Akọrinkéwì, 2/8
Àwọn Ìwé Kíkéréjù, 4/22
Báwo Ni Tẹlifíṣọ̀n Ṣe Léwu Tó? 6/22
De Bẹ́líìtì Ara Ìjókòó Rẹ Nítorí Ààbò, 1/8
Èékánná, 5/22
“Ìfẹ́ Kì Í Kùnà Láé”—Ìwọ Ńkọ́? 5/8
Ìgbà Tí Òkú Kú Ní Gidi, 7/8
Ìgbésí Ayé Tó Ní Ààbò Pípẹ́ Títí, 10/8
Ìpadàbọ̀ Ibi Ìwòran Globe ti London, 6/8
Mo La Ìjàǹbá Ọkọ̀ Òfuurufú Nọnba 801 Já, 3/22
Ǹjẹ́ O Mọ̀, 2/8, 4/8, 6/8, 8/8, 10/8, 12/8
Òfin Ṣe Sọ Pé Kí A Dádọ̀dọ́ Lọ́jọ́ Kẹjọ? 9/8
Wúrà—Ìdí Tí A Fi Kà Á Sí Bàbàrà, 10/8
Yẹra fún Àwọn Ewu Àkókò Ìsinmi, 6/22
SÁYẸ́ǸSÌ
Báwo Ni O Ṣe Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé Sáyẹ́ǹsì Tó? 3/8
Ẹranko Ọlọ́pọlọ-Pípé Lásán Ni Ènìyàn Bí? 6/22
Rọ́bọ́ọ̀tì Ṣàtúpalẹ̀ Pílánẹ́ẹ̀tì Mars, 6/22