Ojú ìwé 2
Àṣà Kíkó Ọmọdé Ṣiṣẹ́—Kò Ní Pẹ́ Dópin! 3-13
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ ọmọdé ni a ń fipá mú láti ṣiṣẹ́ lábẹ́ àwọn ipò tó burú jáì. Ìwà ìkà ni èyí jẹ́ sí àwọn ọmọdé, ó sì ń bu iyì ẹ̀dá kù. Àmọ́, ìrètí wà fún àwọn ọmọdé!
O Ṣeyebíye Lójú Ọlọ́run! 15
Ǹjẹ́ o ti ní ìṣòro ríronú pé o kò já mọ́ nǹkan kan rí? Mímọ̀ nípa ojú tí Ẹlẹ́dàá wa fi ń wò ọ́ yóò tù ọ́ nínú gan-an.
Ọ̀nà Tuntun Tí A Ń Gbà Bá Ikọ́ Ẹ̀gbẹ Jà 23
Iye ènìyàn tó ń pa ju àpapọ̀ àwọn tí àrùn AIDS, ibà, àti àwọn àrùn ilẹ̀ olóoru mìíràn ń pa jákèjádò ayé lọ. Ṣùgbọ́n àwọn olùwádìí ní àwọn ṣì lè rí nǹkan ṣe sí i. Bíi ti báwo?
[Àwòrán ẹ̀yìn ìwé]
Ẹ̀yìn ìwé: Wọ́n ń kó bíríkì ní Gúúsù Amẹ́ríkà
[Credit Line]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: FỌ́TÒ UN 145234/Jean Pierre Laffont
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 2]
Wọ́n ń hun ẹní ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà
[Credit Line]
FỌ́TÒ UN 148040/Jean Pierre Laffont
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fọ́tò: WHO/Thierry Falise