Ojú ìwé 2
Bí O Ṣe Ń Gbé Ìgbésí Ayé Rẹ Ha Ń Pa Ẹ́ Lọ Bí? 3-11
Ìlera ara, ti ọpọlọ, àti ti ẹ̀mí lè jẹ́ ìpìlẹ̀ fún ìgbésí ayé aláyọ̀ tó sì lè jẹ́ kéèyàn gbó, kó tọ́. Ipa wo ni ìgbésí ayé rẹ ń ní lórí rẹ?
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . 12
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Fara Da Ìṣáátá?
Ọlọ́run Ló Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ 20
Ka ìròyìn tó gbámúṣé nípa ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn tí a kó lọ sígbèkùn ní Mòsáńbíìkì àti bí wọ́n ṣe pa ìwà títọ́ mọ́ sí Ọlọ́run.