Ojú ìwé 2
Ṣé Àyànmọ́ Ló Ń Darí Ayé Rẹ? 3-10
Ṣé agbára kan tí a kò lè fojú rí ló ń ṣàkóso ayé rẹ? Tàbí ìwọ ló ń fúnra rẹ yan àwọn ohun tóo fẹ́?
KÍ Ló Dé Tí Mọ́mì Fi Ń Ṣàìsàn Tó Bẹ́è? 23
Rírí i kí òbí rẹ dùbúlẹ̀ ìsàn lè máa já ẹ láyà, ó si lè máa dùn ẹ́. Báwo lo ṣe lè fara dà á?
Ìṣọ̀kan Ìjọsìn Nínú Ìgbéyàwó—Ìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì 26
Kí ni ojú ìwòye Bíbélì nípa èyí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Joard/Sipa Press