Ojú ìwé 2
Ìgbàgbọ́ Nínú Ohun Asán—Èé Ṣe Tó Fi Léwu Gan-an? 3-11
Inú ayé oníyèméjì là ń gbé, síbẹ̀ ṣe ni ìgbàgbọ́ nínú ohun asán túbọ̀ ń gbilẹ̀, àní ó jọ pé kò gbilẹ̀ tó báyìí rí. Kí ló fà á? Ṣóòótọ́ lewu wà nínú ohun tó gbilẹ̀ tó báyìí, tí tẹrú-tọmọ sì tẹ́wọ́ gbà?
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . 17
Kí Ló Dé Tí N Kì Í Túra Ká?
Kí Ló Fà Á Táwọn Kan Fi Ń Ṣàjẹ́? 20
Ìyẹn ni pé àjẹ́, ẹgbẹ́ àjẹ́, àtàwọn Wiccan ṣì wà láyé ọ̀làjú yìí, lọ́dún 1999 yìí? Kí ló dé táwọn kan fi ń ṣàjẹ́ ná?