Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 8, 2002
Àlàáfíà Kárí Ayé—Ṣé Àlá Tí Kò Lè Ṣẹ Ni?
Lọ́dún tó kọjá lọ yìí, àlàáfíà àwọn orílẹ̀-èdè wà nínú ewu ju ti ìgbàkigbà rí lọ. Ǹjẹ́ àlàáfíà kárí ayé lè ṣeé ṣe? Tó bá máa ṣeé ṣe, báwo?
3 Ṣé Ogun Ló Ń Gbé Lárugẹ Ni Àbí Àlàáfíà?
9 Àlàáfíà Kárí Ayé Kì í Ṣe Àlá Tí Kò Lè Ṣẹ o!
13 Ohun Kan Tó Jẹ́ Àdámọ́ Gbogbo Èèyàn
15 Kí Ló Dé Táwọn Èèyàn Ń Fi Àwọn Ẹ̀sìn Tó Ti Wà Látayébáyé Sílẹ̀?
18 Ṣé “Àdábọwọ́ Ìsìn” Ló Máa Yanjú Ọ̀rọ̀ Náà?
20 Ọ̀nà Tó Dára Jù Lọ Láti Rí Ìtẹ́lọ́rùn Tẹ̀mí
29 Ẹ̀jẹ̀ Ríru—Bá A Ṣe Lè Dènà Rẹ̀ àti Bá A Ṣe Lè Kápá Rẹ̀
Kí Ló Dé Tí Àjọgbé Èmi àti Alábàágbé Mi Fi Nira? 10
Lónìí, nítorí ìdí kan tàbí òmíràn, àwọn èèyàn sábàá máa ń ní ẹni tí wọ́n á jọ máa gbé yàrá. Gbé àwọn ìpèníjà tó wà níbẹ̀ yẹ̀ wò.
Oúnjẹ Aṣaralóore Ń Bẹ Níkàáwọ́ Rẹ 23
Oúnjẹ lọ̀rẹ́ àwọ̀, ó sì ń mára le. Báwo lo ṣe lè mú kí ìlera rẹ sunwọ̀n sí i nípa jíjẹ oúnjẹ tó ń ṣara lóore?