Oro Isaaju
Àwọn kan ń ṣiyè méjì pé bóyá ni Jésù wà, ó sì dá àwọn míì lójú gbangba pé Jésù wà. Àwọn míì sì sọ pé kò sí bí èèyàn ṣe lè mọ̀ bóyá Jésù wà tàbí kò sí.
Ìwé ìròyìn “Jí!” yìí sọ àwọn ẹ̀rí tó fi hàn pé Jésù wà lóòótọ́.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.