Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
“Jẹ́ Kí Ijọba Rẹ Dé”
Fun ọ̀pọ̀ ọ̀rúndún ni awọn olufẹ Ọlọrun ati ododo ti ń gbadura pe, “Jẹ́ kí ijọba rẹ dé.” Awọn ìṣẹ̀lẹ̀ agbaye tí ń mú asọtẹlẹ Bibeli ṣẹ fihan pe Ijọba Ọlọrun ti kù sí dẹ̀dẹ̀ nisinsinyi. A nírètí pe iwe yii yoo ràn ọ lọwọ lati nàgà fun ìpín kan ninu awọn ibukun titobilọla tí Ijọba naa yoo pèsè fun araye níhìn-ín lori ilẹ̀-ayé wa gan-an.
—Láti Ọwọ́ Àwọn Olùṣèwéjáde