Koko-Ẹkọ Inu Iwe
OJU-IWE ORI
21 3 Ohun Tí Ijọba naa Tumọsi fun Ilẹ̀-ayé Wa
29 4 Ijọba naa “Dé”—Lati Ibo?
37 5 Ijọba naa—Eeṣe Tí Ó Fi Pẹ́ Tobẹẹ ní ‘Dídé’?
56 7 Dídá Messia, Ọba naa Mọ̀yàtọ̀
78 9 Awọn Ajogún Ijọba Pa Ìwàtítọ́ Mọ́
105 12 “Awọn Ọjọ Ikẹhin” ati Ijọba Naa
117 13 Ẹlẹ́ṣin Ijọba naa Gẹṣin
127 14 Ọba naa Jọba!
141 15 Awọn Aduroṣinṣin Alágbàwí Ijọba Naa
151 16 “Ogunlọgọ Nla Eniyan” Kókìkí Ọba Naa
162 17 Ọba naa Jà ní Armageddoni
186 Ọrọ-Afikun
AKIYESI: Ayafi bi a bá fihàn pe omiran ni, awọn ẹsẹ Iwe Mimọ ti a fayọ ninu iwe yii jẹ lati inu Bibeli Mimọ ni èdè Yoruba, itẹjade ti 1960, ni àkọtọ́ ti ode-oni. Nibi ti a bá ti fi NW hàn tẹ̀lé ẹsẹ Bibeli kan tí a fayọ, o fihàn pe a ṣe itumọ naa lati inu Bibeli èdè Gẹẹsi ti New World Translation of the Holy Scriptures, Itẹjade Titun ti 1984.
Ní isopọ pẹlu awọn ọjọ iṣẹlẹ, ìkékúrú naa B.C.E. tumọsi “Ṣaaju Sanmani Tiwa,” C.E. sì tumọsi “Ní Sanmani Tiwa.”