Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Ojú Ìwé Ìran Orí
15 3 Àwọn Ohun Tó Gbọ́dọ̀ Ṣẹlẹ̀ Láìpẹ́
22 1 5 Jòhánù Rí Jésù Tí Ọlọ́run Ti Ṣe Lógo
27 1 6 A Rí Ìtumọ̀ Àṣírí Ọlọ́wọ̀ Kan
33 1 7 Tún Padà Ní Ìfẹ́ Tó O Ní Níṣàájú!
37 1 8 Lílàkàkà Láti Jẹ́ Aṣẹ́gun
41 1 9 Bá A Ṣe Lè Di Orúkọ Jésù Mú Ṣinṣin
47 1 10 Bá A Ṣe Lè Kórìíra “Àwọn Ohun Ìjìnlẹ̀ Sátánì”
54 1 11 Ǹjẹ́ Orúkọ Rẹ Wà Nínú Ìwé Ìyè?
58 1 12 “Máa Bá A Nìṣó Ní Dídi Ohun Tí Ìwọ Ní Mú Ṣinṣin”
66 1 13 Ra Wúrà Tí A Fi Iná Yọ́ Mọ́
74 2 14 Ògo Ìtẹ́ Jèhófà ní Ọ̀run
82 2 15 “Ta Ni Ó Yẹ Láti Ṣí Àkájọ Ìwé Náà?”
89 3 16 Àwọn Ẹlẹ́ṣin Mẹ́rin Tí Ń Sáré Kútúpà Kútúpà!
100 3 17 ‘Àwọn Ọkàn Tí A Pa’ Gba Èrè
104 3 18 Àwọn Ìsẹ̀lẹ̀ ní Ọjọ́ Olúwa
113 4 19 Fífi Èdìdì Di Ísírẹ́lì Ọlọ́run
119 4 20 Ogunlọ́gọ̀ Ńlá
129 5 21 Àwọn Ìyọnu Tó Wá Sórí Àwọn Oníṣọ́ọ̀ṣì Látọ̀dọ̀ Jèhófà
142 5 22 Ègbé Àkọ́kọ́—Àwọn Eéṣú
148 5 23 Ègbé Kejì—Agbo Àwọn Agẹṣinjagun
155 6 24 Ìhìn Tó Dùn Tó sì Tún Korò
161 6 25 A Mú Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì Náà Sọ Jí
171 6 26 Àṣírí Mímọ́ ti Ọlọ́run—Ọ̀nà Ológo Tó Gbà Parí!
177 7 27 A Bí Ìjọba Ọlọ́run!
186 8 28 Bíbá Ẹranko Rírorò Méjì Wọ̀jà
198 9 29 Kíkọ Orin Ayọ̀ Ìṣẹ́gun Tuntun
205 9 30 “Bábílónì Ńlá Ti Ṣubú!”
215 10 31 Àwọn Iṣẹ́ Jèhófà Tóbi Wọ́n sì Jẹ́ Àgbàyanu
221 10 32 Ìbínú Ọlọ́run Parí
235 11 33 Ṣíṣèdájọ́ Aṣẹ́wó Burúkú Náà
246 11 34 A Rí Ojútùú Ohun Ìjìnlẹ̀ Kan Tó Ṣeni Ní Kàyéfì
251 11 35 Pípa Bábílónì Ńlá Run
258 12 36 Ìlú Ńlá Náà Pa Run
267 12 37 Ọ̀fọ̀ àti Ayọ̀ Nígbà Ìparun Bábílónì
272 12 38 Ẹ Yin Jáà Nítorí Ìdájọ́ Rẹ̀!
279 13 39 Ọba Ajagun Náà Ṣẹ́gun ní Amágẹ́dọ́nì
286 14 40 Títẹ Orí Ejò Náà Fọ́
295 15 41 Ọjọ́ Ìdájọ́ Ọlọ́run—Àbájáde Rẹ̀ Aláyọ̀!
301 15 42 Ọ̀run Tuntun àti Ayé Tuntun
305 16 43 Ìlú Ológo
Gbogbo ìwé Ìṣípayá látòkèdélẹ̀ ni a ṣàlàyé nínú ìtẹ̀jáde yìí. Àwọn ẹsẹ tí a ń sọ̀rọ̀ lórí wọn la fi lẹ́tà dídúdú kirikiri kọ.