ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • re ojú ìwé 1-3
  • Àkọlé Ìwé/Ojú Ìwé Òǹṣèwé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àkọlé Ìwé/Ojú Ìwé Òǹṣèwé
  • Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
  • Ìsọ̀rí
  • ÌWÉ YÌÍ JẸ́ TI ․․․․․․․․․․․․․․․․
Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
re ojú ìwé 1-3

Àkọlé Ìwé/Ojú Ìwé Òǹṣèwé

Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!

ÌWÉ YÌÍ JẸ́ TI ․․․․․․․․․․․․․․․․

A Tún Un Tẹ̀ ní Ọdún 2006

A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.

Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ. Níbi tí NW bá ti tẹ̀ lé àyọlò, ó fi hàn pé ìtumọ̀ náà wá láti inú Bíbélì New World Translation of the Holy Scriptures—With References

Ibi Tá A Ti Mú Àwọn Àwòrán

A to àwọn àwòrán lẹ́sẹẹsẹ ní ìbámu pẹ̀lú ojú ìwé tí wọ́n ti fara hàn, nígbà tó bá sì pọn dandan, a tò wọ́n gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe fara hàn tẹ̀ léra ní ojú ìwé tí wọ́n wà (bẹ̀rẹ̀ láti òsì sí ọ̀tún láti apá òkè).

Cooper-Hewitt Museum; a ya àwòrán yìí nípa wíwo ohun tó wà nínú case 9, panel A: Ojú ìwé 59

National Aeronautics and Space Administration, Washington, D.C.: Ojú ìwé 138, 293

Pictorial Archive (Near Eastern History) Est.: Ojú ìwé 23 (àwòrán ara ojú ìwé yẹn gan-an, 1, 4, 10)

Pictorial Archive (Near Eastern History) Est., and Survey of Israel; a gbé e karí àwòrán ilẹ̀ tí ẹ̀tọ́ rẹ̀ jẹ́ tiwọn: Ojú ìwé 236

Staatliche Museen zu Berlin; a lò ó nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda wọn: Ojú ìwé 43 (1, 2, 3)

“Aláyọ̀ ni ẹni tí ń ka àwọn ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ yìí sókè àti àwọn tí ń gbọ́, tí wọ́n sì ń pa àwọn ohun tí a kọ sínú rẹ̀ mọ́; nítorí àkókò tí a yàn kalẹ̀ ti sún mọ́lé.”—Ìṣípayá 1:3

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́