Kókó Ẹ̀kọ́ Inú Ìwé
Ojú Ìwé
5 Káàbọ̀ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
9 Ní Inú Dídùn sí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
13 “Ẹ Máa Fiyè sí Bí Ẹ Ṣe Ń Fetí Sílẹ̀”
17 O Lè Mú Kí Agbára Ìrántí Rẹ Já Fáfá
43 Bí Akẹ́kọ̀ọ́ Ṣe Lè Múra Iṣẹ́ Ilé Ẹ̀kọ́ Sílẹ̀
47 Mímúra Ọ̀rọ̀ Tó O Máa Sọ fún Ìjọ Sílẹ̀
52 Mímúra Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn Sílẹ̀
56 Kọ́ Bí A Ṣe Ń Jẹ́ Olùkọ́ Tó Múná Dóko
62 Bí A Ṣe Lè Mú Ọ̀nà Tí A Gbà Ń Fọ̀rọ̀ Wérọ̀ Sunwọ̀n Sí I
78 Ètò Sísọni Di Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ àti Olùkọ́ni
Ohun Tí Yóò Mú Ọ Tẹ̀ Síwájú
Ojú Ìwé Ẹ̀kọ́
101 6 Títẹnumọ́ Ọ̀rọ̀ Bó Ṣe Yẹ
105 7 Títẹnumọ́ Àwọn Kókó Pàtàkì
111 9 Yíyí Ohùn Padà Nínú Ọ̀rọ̀ Sísọ
115 10 Ìtara
118 11 Fífi Ọ̀yàyà Sọ̀rọ̀ àti Fífi Bí Nǹkan Ṣe Rí Lára Ẹni Hàn
121 12 Ìfaraṣàpèjúwe àti Ìrísí Ojú
128 14 Sọ̀rọ̀ Bí Ọlọ́run Ṣe Dá Ọ
131 15 Ìrísí Tó Dára
135 16 Ìbàlẹ̀ Ọkàn
143 18 Lílo Bíbélì Láti Fi Dáhùn Ìbéèrè
145 19 Fúnni Níṣìírí Láti Lo Bíbélì
147 20 Nínasẹ̀ Ìwé Mímọ́ Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́
150 21 Fífi Ìtẹnumọ́ Yíyẹ Ka Ìwé Mímọ́
153 22 Lílo Ìwé Mímọ́ Bí Ó Ti Yẹ
157 23 Jẹ́ Kí Àwùjọ Rí Bí Ọ̀rọ̀ Rẹ Ṣe Wúlò
170 26 Ṣíṣàlàyé Ọ̀rọ̀ Lẹ́sẹẹsẹ
174 27 Sísọ̀rọ̀ Láìgbáralé Àkọsílẹ̀
179 28 Sísọ̀rọ̀ Bí Ẹní Ń Báni Fọ̀rọ̀ Wérọ̀
181 29 Ìró Ohùn
186 30 Bó O Ṣe Lè Fi Hàn Pé Ire Àwọn Ẹlòmíràn Ń Jẹ Ọ́ Lógún
190 31 Bíbọ̀wọ̀fúnni
197 33 Lo Ọgbọ́n Inú Síbẹ̀ Dúró Lórí Òtítọ́
202 34 Sọ Ohun Tó Ń Gbéni Ró Tó sì Ṣàǹfààní
206 35 Sísọ Àsọtúnsọ Láti Tẹnu Mọ́ Ọ̀rọ̀
212 37 Mú Kí Kókó Ọ̀rọ̀ Fara Hàn Kedere
215 38 Ìnasẹ̀ Ọ̀rọ̀ Tí Ń Múni Nífẹ̀ẹ́ sí Ọ̀rọ̀
226 41 Jẹ́ Kí Àlàyé Ọ̀rọ̀ Rẹ Yéni
230 42 Jẹ́ Kí Àwùjọ Rí Ẹ̀kọ́ Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ
234 43 Mú Ọ̀rọ̀ Rẹ Jáde Láti Ibi Tí A Ti Yanṣẹ́ fún Ọ
236 44 Lílo Ìbéèrè Lọ́nà Tó Múná Dóko
240 45 Àpèjúwe àti Àpẹẹrẹ Tí Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́
244 46 Àpèjúwe Tí A Gbé Ka Ohun Táwọn Èèyàn Mọ̀
247 47 Lílo Ohun Tí A Lè Fojú Rí Lọ́nà Tó Múná Dóko
251 48 Ọ̀nà Tí Ò Ń Gbà Fèrò Wérò
258 50 Rírí I Dájú Pé Ọ̀rọ̀ Wọni Lọ́kàn
263 51 Lo Àkókò Tó Ṣe Rẹ́gí, Pín Àkókò Bó Ṣe Yẹ
265 52 Gbígbani-níyànjú Lọ́nà Tó Múná Dóko
268 53 Fún Àwùjọ Ní Ìṣírí àti Okun
282 Ìlànà fún Àwọn Alábòójútó Ilé Ẹ̀kọ́
286 Atọ́ka