Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Ojú Ìwé Orí
ÌSỌ̀RÍ 1—Ọlọ́run Lè Ràn Ọ́ Lọ́wọ́ Láti Múra Sílẹ̀ fún Ọjọ́ Ńlá Rẹ̀
5 1. Iṣẹ́ Tí Jèhófà Rán sí Àwọn Èèyàn Ayé Ọjọ́un Ṣì Wà fún Wa Lónìí
14 2. Àwọn Wòlíì Tí Wọ́n Jíṣẹ́ Tó Lè Ṣe Wá Láǹfààní
29 3. Ọjọ́ Jèhófà—Ẹṣin Ọ̀rọ̀ Pàtàkì
ÌSỌ̀RÍ 2—Mọ Jèhófà Kó O sì Máa Sìn Ín
43 4. Jèhófà—Ọlọ́run Tó Ń Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Tó sì Ń Mú Àsọtẹ́lẹ̀ Ṣẹ
56 5. “Wá Jèhófà” Nípa Jíjọ́sìn Rẹ̀ Lọ́nà Tó Fẹ́
70 6. ‘Jíjẹ́ Kí Ìdájọ́ Òdodo Tú Jáde’ Ṣe Pàtàkì Láti Lè Mọ Ọlọ́run
83 7. Máa Sin Jèhófà ní Ìbámu Pẹ̀lú Àwọn Ìlànà Tó Fi Lélẹ̀
ÌSỌ̀RÍ 3—Jẹ́ Kí Ìwà Rẹ àti Bó O Ṣe Ń Bá Àwọn Ẹlòmíràn Lò Máa Múnú Ọlọ́run Dùn
97 8. ‘Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Rẹ?’
111 9. Máa Bá Àwọn Ẹlòmíràn Lò Lọ́nà Tí Ọlọ́run Fẹ́
124 10. Ohun Tó Yẹ Kó O Ṣe Kó O Lè Ní Ìdílé Tó Ń Múnú Ọlọ́run Dùn
ÌSỌ̀RÍ 4—Máa Fayọ̀ Retí Ọjọ́ Jèhófà
139 11. Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Jèrè Ìyè—Ǹjẹ́ Ìwọ Náà Fẹ́ Bẹ́ẹ̀?
152 12. “Máa Bá A Nìṣó Ní Fífojú Sọ́nà fún Un”