Àlàyé
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ni . . .
ÀWỌN ẸSẸ ÌWÉ MÍMỌ́
tó ṣàlàyé àwọn kókó pàtàkì
ÌMỌ̀RÀN
àwọn àbá tó máa jẹ́ kó o lè kẹ́sẹ járí
ṢÓ O MỌ̀ PÉ . . .
àwọn kókó pàtàkì tó máa mú kó o ronú jinlẹ̀
OHUN TÍ MÀÁ ṢE!
ibẹ̀ lo máa kọ bó o ṣe máa lo ohun tó o bá kà nínú ìwé yìí sí
KÍ LÈRÒ Ẹ?
àwọn ìbéèrè tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ronú lórí ohun tó o ti kà
Ní Àfikún . . .
OHUN TÍ MO RÒ
ojú ewé yìí la fi parí apá kọ̀ọ̀kan nínú ìwé yìí, wàá sì lè kọ ohun tó o rò síbẹ̀
ÀWÒKỌ́ṢE
àwọn èèyàn kan nínú Bíbélì tó o lè fara wé