Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
Ìwé yìí kì í ṣe títà. Ńṣe là ń tẹ̀ ẹ́ jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ
A Tẹ̀ Ẹ́ ní February 2017
Yoruba (bm-YR)
© 2009
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA