Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Apá
1 Ẹlẹ́dàá Dá Èèyàn Sínú Párádísè
4 Ọlọ́run Bá Ábúráhámù Dá Májẹ̀mú
5 Ọlọ́run Bù Kún Ábúráhámù àti Ìdílé Rẹ̀
7 Ọlọ́run Dá Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Nídè
8 Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Wọ Ilẹ̀ Kénáánì
9 Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Sọ Pé Àwọn Fẹ́ Ọba
11 Àwọn Orin Onímìísí, Tó Ń Tuni Nínú, Tó sì Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́
12 Ọgbọ́n Ọlọ́run Tó Ń Mú Ká Wà Láàyè
13 Àwọn Ọba Rere Àtàwọn Ọba Búburú
14 Ọlọ́run Gbẹnu Àwọn Wòlíì Rẹ̀ Sọ̀rọ̀
15 Wòlíì Kan Tó Wà Nígbèkùn Rí Ohun Tó Ń Bọ̀ Wá Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú Nínú Ìran
16 Mèsáyà Dé
17 Jésù Kọ́ni Nípa Ìjọba Ọlọ́run
19 Jésù Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Tí Ìmúṣẹ Rẹ̀ Rìn Jìnnà
21 Jésù Jíǹde!
22 Àwọn Àpọ́sítélì Wàásù Láìbẹ̀rù