Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
OJÚ ÌWÉ ORÍ
9 1. “Bí Ó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Ó Kú, Ó Ń Sọ̀rọ̀ Síbẹ̀”—ÉBẸ́LÌ
17 2. Ó “Bá Ọlọ́run Tòótọ́ Rìn”—NÓÀ
25 3. “Baba Gbogbo Àwọn Tí Wọ́n Ní Ìgbàgbọ́”—ÁBÚRÁMÙ
33 4. “Ibi Tí O Bá Lọ Ni Èmi Yóò Lọ”—RÚÙTÙ
42 5. “Obìnrin Títayọ Lọ́lá”—RÚÙTÙ
51 6. Ó Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀ fún Ọlọ́run Nínú Àdúrà—HÁNÀ
59 7. Ó “Ń Bá A Lọ ní Dídàgbà Lọ́dọ̀ Jèhófà”—SÁMÚẸ́LÌ
67 8. Ó Lo Ìfaradà Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Wọ́n Já A Kulẹ̀—SÁMÚẸ́LÌ
76 9. Ó Hùwà Ọlọgbọ́n—ÁBÍGẸ́LÌ
84 10. Ó Gbèjà Ìjọsìn Mímọ́—ÈLÍJÀ
92 11. Ó Ṣọ́nà, Ó sì Ní Sùúrù—ÈLÍJÀ
99 12. Ọlọ́run Rẹ̀ Tù Ú Nínú—ÈLÍJÀ
108 13. Ó Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ̀—JÓNÀ
116 14. Ó Kọ́ Ìdí Tó Fi Yẹ Kó Jẹ́ Aláàánú—JÓNÀ
125 15. Ó Gbèjà Àwọn Èèyàn Ọlọ́run—Ẹ́SÍTÉRÌ
135 16. Ó Lo Ọgbọ́n àti Ìgboyà, Kò sì Mọ Tara Rẹ̀ Nìkan—Ẹ́SÍTÉRÌ
145 17. “Wò Ó! Ẹrúbìnrin Jèhófà!”—MÀRÍÀ
153 18. Ó Dé ‘Ìparí Èrò Nínú Ọkàn Rẹ̀’—MÀRÍÀ
162 19. Ó Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Ní Ìfaradà—JÓSẸ́FÙ
172 20. “Mo Ti Gbà Gbọ́”—MÀTÁ
180 21. Ó Borí Ìbẹ̀rù àti Iyè Méjì—PÉTÉRÙ
188 22. Ó Dúró Ṣinṣin Nígbà Ìdánwò—PÉTÉRÙ
196 23. Ó Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ìdáríjì Lọ́dọ̀ Ọ̀gá Rẹ̀—PÉTÉRÙ
206 Ìparí