Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
Ìwé yìí jẹ́ ti ․․․․․
© 2013
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA
Àwa òǹṣèwé
WATCHTOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF NEW YORK, INC.
Brooklyn, New York, U.S.A.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní May 2013
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ. Níbi tí NW ba ti tẹ̀ lé àyọlò, ó fi hàn pé ìtumọ̀ náà wá láti inú Bíbélì New World Translation of the Holy Scriptures—With References.