ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm18 ojú ìwé 2-3
  • Friday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Friday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2018
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2018
CO-pgm18 ojú ìwé 2-3
Jóṣúà ń ka ìwé Òfin; Dáfídì ta kànnàkànnà sí Góláyátì

Friday

“Jẹ́ onígboyà àti alágbára gidigidi”—JÓṢÚÀ 1:7

ÒWÚRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 110 àti Àdúrà

  • 9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Jèhófà Ló Ń Jẹ́ Ká Ní Ìgboyà Tòótọ́ (Sáàmù 28:7; 31:24; 112:7, 8; 2 Tímótì 1:7)

  • 10:10 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ìdí Tí Àwa Kristẹni Tòótọ́ Fi Nílò Ìgboyà

    • Láti Wàásù (Ìṣípayá 14:6)

    • Láti Máa Jẹ́ Mímọ́ (1 Kọ́ríńtì 16:13, 14)

    • Láti Má Ṣe Dá Sí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú (Ìṣípayá 13:​16, 17)

  • 11:05 Orin 126 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: “Jẹ́ Onígboyà àti Alágbára Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀”! (1 Kíróníkà 28:1-20; 1 Sámúẹ́lì 16:1-23; 17:1-51)

  • 11:45 ‘Ohun Ìjà Yòówù Tí Wọ́n Bá Ṣe sí Ọ Kì Yóò Ṣe Àṣeyọrí’ (Aísáyà 54:17; Sáàmù 118:5-7)

  • 12:15 Orin 61 àti Àkókò Ìsinmi

Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò ń jáde bọ̀ látinú iná láìfarapa; àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ń pe lẹ́tà fún Tímótì nígbà tí wọn ò jẹ́ kó jáde nílé

Ọ̀SÁN

  • 1:25 Fídíò Orin

  • 1:35 Orin 69

  • 1:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tí Kì Í Jẹ́ Kí Ìgboyà Lágbára Àtohun Tó Ń Jẹ́ Kí Ìgboyà Túbọ̀ Lágbára

    • Àìnírètí àti Ìrètí (Sáàmù 27:​13, 14)

    • Ìráhùn àti Ìdúpẹ́ (Sáàmù 27:1-3)

    • Eré Ìnàjú Tí Kò Bójú Mu àti Iṣẹ́ Ìwàásù (Sáàmù 27:4)

    • Ẹgbẹ́ Burúkú àti Ẹgbẹ́ Rere (Sáàmù 27:5; Òwe 13:20)

    • Ọgbọ́n Ayé àti Ìdákẹ́kọ̀ọ́ (Sáàmù 27:11)

    • Iyè Méjì àti Ìgbàgbọ́ (Sáàmù 27:7-10)

  • 3:10 Orin 55 àti Ìfilọ̀

  • 3:20 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tí Wọ́n Yááfì; Bí Ọlọ́run Ṣe San Wọ́n Lẹ́san

    • Hananáyà, Míṣáẹ́lì àti Asaráyà (Dáníẹ́lì 1:​11-13; 3:27-29)

    • Ákúílà àti Pírísílà (Róòmù 16:3, 4)

    • Sítéfánù (Ìṣe 6:11, 12)

  • 3:55 “Ẹ Mọ́kànle! Mo Ti Ṣẹ́gun Ayé” (Jòhánù 16:33; 1 Pétérù 2:​21, 22)

  • 4:15 Àwọn Ọmọ Ogun Kristi Onígboyà (2 Kọ́ríńtì 10:4, 5; Éfésù 6:12-18; 2 Tímótì 2:3, 4)

  • 4:50 Orin 22 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́