Saturday
‘Wọ́n ń fi ìgboyà púpọ̀ sí i hàn láti sọ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láìbẹ̀rù’—FÍLÍPÌ 1:14
ÒWÚRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 76 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ẹ Jẹ́ Onígboyà . . . - Ẹ̀yin Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì (Ìṣe 8:35, 36; 13:48) 
- Ẹ̀yin Ọ̀dọ́ (Sáàmù 71:5; Òwe 2:11) 
- Ẹ̀yin Akéde (1 Tẹsalóníkà 2:2) 
- Ẹ̀yin Tọkọtaya (Éfésù 4:26, 27) 
- Ẹ̀yin Òbí (1 Sámúẹ́lì 17:55) 
- Ẹ̀yin Aṣáájú-Ọ̀nà (1 Àwọn Ọba 17:6-8, 12, 16) 
- Ẹ̀yin Alàgbà Ìjọ (Ìṣe 20:28-30) 
- Ẹ̀yin Àgbàlagbà (Dáníẹ́lì 6:10, 11; 12:13) 
 
- 10:50 Orin 119 àti Ìfilọ̀ 
- 11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Nígboyà, Kì Í Ṣe Àwọn Ojo! - Má Tẹ̀ Lé Àwọn Ìjòyè Mẹ́wàá, Tẹ̀ Lé Jóṣúà àti Kálébù (Númérì 14:7-9) 
- Má Tẹ̀ Lé Àwọn Aráàlú Mérósì, Tẹ̀ Lé Jáẹ́lì (Àwọn Onídàájọ́ 5:23) 
- Má Tẹ̀ Lé Àwọn Wòlíì Èké, Tẹ̀ Lé Mikáyà (1 Àwọn Ọba 22:14) 
- Má Tẹ̀ Lé Úríjà, Tẹ̀ Lé Jeremáyà (Jeremáyà 26:21-23) 
- Má Tẹ̀ Lé Ọ̀dọ́kùnrin Ọlọ́rọ̀ Tó Jẹ́ Alákòóso, Tẹ̀ Lé Pọ́ọ̀lù (Máàkù 10:21, 22) 
 
- 11:45 ÌRÌBỌMI: “Àwa Kì Í Ṣe Irú Àwọn Tí Ń Fà Sẹ́yìn”! (Hébérù 10:35, 36, 39; 11:30, 32-34, 36; 1 Pétérù 5:10) 
- 12:15 Orin 38 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 111 
- 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ìgboyà Lára Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá - Kìnnìún (Míkà 5:8) 
- Ẹṣin (Jóòbù 39:19-25) 
- Asín Igbó (Sáàmù 91:3, 13-15) 
- Ẹyẹ Akùnyùnmù (1 Pétérù 3:15) 
- Erin (Òwe 17:17) 
 
- 2:40 Orin 60 àti Ìfilọ̀ 
- 2:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Àwọn Ará Wa Ṣe Ń Fi Hàn Pé Àwọn Nígboyà ní . . . - Áfíríkà (Mátíù 10:36-39) 
- Éṣíà (Sekaráyà 2:8) 
- Yúróòpù (Ìṣípayá 2:10) 
- Amẹ́ríkà Ti Àríwá (Aísáyà 6:8) 
- Oceania (Sáàmù 94:14, 19) 
- Amẹ́ríkà Ti Gúúsù (Sáàmù 34:19) 
 
- 4:15 Jẹ́ Onígboyà àmọ́ Má Ṣe Dá Ara Rẹ Lójú Jù! (Òwe 3:5, 6; Aísáyà 25:9; Jeremáyà 17:5-10; Jòhánù 5:19) 
- 4:50 Orin 3 àti Àdúrà Ìparí