Sunday
‘Ẹ DÚRÓ NÍNÚ ÌFẸ́ ỌLỌ́RUN’—JÚÙDÙ 21
ÒWÚRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 106 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe - Ìfẹ́ Máa Ń Ní Sùúrù àti Inú Rere (1 Kọ́ríńtì 13:4) 
- Ìfẹ́ Kì Í Jowú; Kì Í Fọ́nnu (1 Kọ́ríńtì 13:4) 
- Kì Í Gbéra Ga; Kì Í Hùwà Tí Kò Bójú Mu (1 Kọ́ríńtì 13:4, 5) 
- Kì Í Wá Ire Tirẹ̀ Nìkan; Kì Í Tètè Bínú (1 Kọ́ríńtì 13:5) 
- Kì Í Di Èèyàn Sínú; Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo (1 Kọ́ríńtì 13:5, 6) 
- Ó Máa Ń Yọ̀ Lórí Òtítọ́; Ó Máa Ń Mú Ohun Gbogbo Mọ́ra (1 Kọ́ríńtì 13:6, 7) 
- Ó Máa Ń Gba Ohun Gbogbo Gbọ́; Ó Máa Ń Retí Ohun Gbogbo (1 Kọ́ríńtì 13:7) 
- Ó Máa Ń Fara Da Ohun Gbogbo; Ìfẹ́ Kì Í Yẹ̀ Láé (1 Kọ́ríńtì 13:7, 8) 
 
- 11:10 Orin 150 and àti Ìfilọ̀ 
- 11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Ibo Lo Ti Lè Rí Ìfẹ́ Tòótọ́ Nínú Ayé Tó Kún fún Ìkórìíra Yìí? (Jòhánù 13:34, 35) 
- 11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 12:20 Orin 1 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 124 
- 1:50 FÍÌMÙ: Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú—Apá Kejì (2 Àwọn Ọba 22:3-20; 23:1-25; 2 Kíróníkà 34:3-33; 35:1-19) 
- 2:20 Orin “Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà” àti Ìfilọ̀ 
- 2:30 “Fara Balẹ̀ Kíyè Sí Àwọn Ohun Tí Jèhófà Ṣe Nítorí Ìfẹ́ Rẹ̀ Tí Kì Í Yẹ̀” (Sáàmù 107:43; Éfésù 5:1, 2) 
- 3:30 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí