Sunday
“Jọ́sìn Baba ní ẹ̀mí àti òtítọ́”—Jòhánù 4:23
Àárọ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 140 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Jésù - • A Gbọ́dọ̀ “Bí Ẹnì Kan Látinú Omi àti Ẹ̀mí” (Jòhánù 3:3, 5) 
- • “Kò Sí Èèyàn Kankan Tó Tíì Gòkè Lọ Sọ́run” (Jòhánù 3:13) 
- • “Wá Sínú Ìmọ́lẹ̀” (Jòhánù 3:19-21) 
- • “Èmi Ni” (Jòhánù 4:25, 26) 
- • “Oúnjẹ Mi Ni” (Jòhánù 4:34) 
- • “Àwọn Pápá ti Funfun . . . Wọ́n ti Tó Kórè” (Jòhánù 4:35) 
 
- 11:05 Orin 37 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ṣé Ò Ń Jọ́sìn Ohun Tó O Mọ̀? (Jòhánù 4:20-24) 
- 11:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 12:15 Orin 84 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀sán
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 77 
- 1:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ: - Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 3 - “Èmi Ni” (Jòhánù 3:1–4:54; Mátíù 4:12-20; Máàkù 1:19, 20; Lúùkù 4:16–5:11) 
- 2:35 Orin 20 àti Ìfilọ̀ 
- 2:45 Kí Lo Rí Kọ́? 
- 2:55 Má Ṣe Kúrò Nínú Tẹ́ńpìlì Ńlá Tẹ̀mí Jèhófà! (Hébérù 10:21-25; 13:15, 16; 1 Pétérù 1:14-16; 2:21) 
- 3:45 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí