Wá Ìdáhùn Sí Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- Kí nìdí tí ìfẹ́ fi ṣe pàtàkì ju ìmọ̀ lọ? (1 Kọ́r. 8:1) 
- Bíi táwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run láyé àtijọ́, báwo làwa náà ṣe lè gbé àwọn ará ró? (Róòmù 13:8) 
- Báwo la ṣe lè fìfẹ́ hàn sáwọn tá a bá pàdé lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? (1 Tẹs. 2:7, 8) 
- Báwo la ṣe lè mú kí ìjọ máa dàgbà sí i? (Éfé. 4:1-3, 11-16; 1 Tẹs. 5:11) 
- Báwo la ṣe lè máa fi ìfẹ́ ṣe gbogbo ohun tí a bá ń ṣe? (1 Kọ́r. 16:14) 
© 2019 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania