Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- 1. Báwo la ṣe lè wọnú ìsinmi Ọlọ́run? (Jẹ́n. 2:1-3; Héb. 4:1, 11) 
- 2. Báwo la ṣe lè jẹ́ kí agbára tí “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” ní hàn láyé wa? (1 Tẹs. 2:13; Héb. 4:12) 
- 3. Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kí Jèhófà máa tọ́ wa sọ́nà? (Àìsá. 26:7-9, 15, 20) 
- 4. Kí ló yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ kí Jèhófà bù kún wa? (1 Pét. 1:13-15; 1 Jòh. 5:3) 
- 5. Báwo la ṣe lè mú inú Jèhófà dùn? (Sm. 71:14, 15; Róòmù 12:2; 1 Pét. 4:10) 
- 6. Kí lá jẹ́ ká túbọ̀ máa láyọ̀ bá a ṣe ń sin Jèhófà? (Jòh. 5:17) 
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-brpgm24-YR