Iyèméjì
Tá a bá ń ronú pé bóyá la lè wúlò fún Jèhófà, àkóbá wo nìyẹn lè ṣe fún wa?
Nọ 11:14, 15; 1Ọb 19:1-4; Job 3:3; Jer 15:10
- Àpẹẹrẹ inú Bíbélì: - Da 10:8-11, 18, 19—Wòlíì Dáníẹ́lì ò lókun mọ́, àmọ́ nígbà tí áńgẹ́lì kan rán an létí pé ó ṣeyebíye lójú Jèhófà, ó pa dà lókun 
- Mt 10:29-31—Jésù sọ àpèjúwe kan nípa àwọn ológoṣẹ́ láti jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀rọ̀ wa jẹ Jèhófà lógún, ó sì nífẹ̀ẹ́ wa 
 
- Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó lè tù wá nínú: