Ìwà Rere
Kí ló fi hàn pé ẹni rere ni Jèhófà?
Tún wo Jer 31:12, 13; Sek 9:16, 17
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
Ẹk 33:17-20; 34:5-7—Jèhófà fi ìran kan han Mósè tó jẹ́ kó rí i pé ẹni rere ni Jèhófà, Mósè tún gbọ́ nípa àwọn ìwà àti ìṣe míì tí Jèhófà ní
Mk 10:17, 18—Jésù sọ pé ọ̀dọ̀ Jèhófà ni gbogbo nǹkan rere ti wá, òun ló sì lè pinnu ohun tó dáa àti ohun tí kò dáa