ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 110
  • Orúkọ Oyè

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Orúkọ Oyè
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 110

Orúkọ Oyè

Ṣó yẹ káwa Kristẹni máa lo orúkọ oyè fáwọn tó jẹ́ alábòójútó nínú ìjọ?

Jo 5:41

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Lk 18:18, 19—Bó tiẹ̀ jẹ́ pé èèyàn dáadáa ni Jésù, kò gbà káwọn èèyàn pe òun ní “Olùkọ́ Rere,” torí ó gbà pé Jèhófà nìkan lẹ́ni rere

Kí nìdí táwa Kristẹni kì í fi í pe àwọn tó jẹ́ alábòójútó nínú ìjọ láwọn orúkọ oyè bíi “Baba” tàbí “Aṣáájú”?

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mt 23:9-12—Jésù sọ pé a ò gbọ́dọ̀ lo àwọn orúkọ oyè bíi “Baba” tàbí “Aṣáájú” nínú ìjọsìn wa

    • 1Kọ 4:14-17—Bíi bàbá ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù jẹ́ fún ọ̀pọ̀ èèyàn, síbẹ̀ kò sí ẹnì kankan tó pè é ní Baba wa Pọ́ọ̀lù tàbí orúkọ oyè míì

Kí nìdí tó fi bá a mu pé káwa Kristẹni máa ṣe bí ọmọ ìyá, ká sì máa pe ara wa ní arákùnrin àti arábìnrin?

Mt 23:8

Tún wo Iṣe 12:17; 18:18; Ro 16:1

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mt 12:46-50—Jésù jẹ́ kó ṣe kedere pé àwọn tó ń sin Jèhófà ni arákùnrin àti arábìnrin òun

Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni máa lo orúkọ oyè fáwọn aláṣẹ ìjọba, olóṣèlú, adájọ́, àtàwọn aláṣẹ míì?

Ro 13:1, 7; 1Pe 2:17

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Iṣe 26:1, 2, 25—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù lo orúkọ oyè fáwọn aláṣẹ ìjọba bí Ágírípà àti Fẹ́sítọ́ọ̀sì

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́