ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 108-110
  • Òmìnira

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Òmìnira
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 108-110

Òmìnira

Ta ni ẹnì kan ṣoṣo tí kò sí ẹni tó lè yẹ̀ ẹ́ lọ́wọ́ wò láyé àtọ̀run?

Ais 40:13, 15; Ro 9:20, 21

Tún wo Ro 11:33-36

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Da 4:29-35—Bó tìẹ jẹ́ pé alágbára ni Ọba Nebukadinésárì, ó rí i pé Jèhófà ló lágbára jù lọ, ẹnikẹ́ni ò sì lè yẹ̀ ẹ́ lọ́wọ́ wò

    • Ais 45:6-12—Jèhófà ni Ẹlẹ́dàá, torí náà kò pọn dandan pé kó ṣàlàyé ìdí tó fi ń ṣe àwọn nǹkan

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Jèhófà lè ṣe ohunkóhun tó bá wù ú, àwọn nǹkan wo ni kò ní ṣe láé?

Di 32:4; Job 34:10; Tit 1:2

Tún wo Ro 9:14

Kí nìdí tá ò fi lè máa ṣe bó ṣe wù wá láìsí ẹni tó máa yẹ̀ wá lọ́wọ́ wò?

Jẹ 1:28; Ro 13:1, 5, 7; 1Kọ 11:3; Heb 13:17

Kí ló lè mú kí Kristẹni kan pinnu pé òun ò ní ṣe ohun kan bó tiẹ̀ jẹ́ pé nǹkan yẹn ò burú?

Mt 7:12; 1Kọ 8:13

Kí nìdí tá a fi lè sọ pé àwa ìránṣẹ́ Jèhófà lómìnira?

Jo 8:31, 32; 2Kọ 3:17

Tún wo Ga 2:4; 4:25, 26; 5:1

Kí nìdí táwọn tó ń sin Jèhófà fi máa ń láyọ̀?

Sm 40:8

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 18:3; Heb 11:8-10—Ábúráhámù ò gbàgbé ìlérí tí Jèhófà ṣe fún un, ìyẹn sì mú kó máa sin Jèhófà nìṣó

    • Heb 11:24-26—Mósè pinnu pé Jèhófà lòun máa sìn, torí náà Jèhófà jẹ́ káyé ẹ̀ dáa, ó fún un lómìnira, ó sì jẹ́ kó nírètí ọjọ́ iwájú

Kí lohun tí Jèhófà gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ ẹ̀?

Ro 6:16-18, 22; 8:2

Kí nìdí tí kò fi yẹ káwa Kristẹni ṣi òmìnira wa lò?

Ga 5:13; 1Pe 2:16

Kí ló lè mú kí Kristẹni kan má lo òmìnira ẹ̀?

1Kọ 9:19; 10:23, 24, 32, 33; 13:4, 5

Báwo ni ìwàásù wa ṣe ń sọ àwọn èèyàn dòmìnira?

Lk 4:18; Jo 8:32, 36

Òmìnira wo ni Jèhófà sọ pé a máa ní lọ́jọ́ iwájú?

Ro 8:21; Ifi 21:3, 4

Kí nìdí tá a fi lè sọ pé ẹni tó bá ń ṣe bó ṣe wù ú ti sọ ara ẹ̀ dẹrú?

Jo 8:34; 2Pe 2:18-20

Báwo la ṣe mọ̀ pé bákan náà làwa èèyàn rí lójú Ọlọ́run?

1Kọ 7:22; Ga 3:28; Kol 3:10, 11

Tún wo 1Kọ 12:13

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́