Aájò Àlejò Ro 12:13; Heb 13:2; 1Pe 4:9 Tún wo 1Ti 3:2; Tit 1:8 Àpẹẹrẹ inú Bíbélì: Jẹ 18:1-8—Ábúráhámù àti Sérà ṣe àwọn áńgẹ́lì lálejò Iṣe 16:13-15—Lìdíà rọ àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù àtàwọn tó ń bá a rìnrìn àjò pé kí wọ́n wá sílé òun, kóun lè ṣe wọ́n lálejò