Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà
Àárọ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 58 àti Àdúrà 
- 10:00 Ẹ Káàbọ̀, Ẹ̀yin Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà! 
- 10:15 Ẹ Máa Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà 
- 10:30 Jẹ́ Kí Ọmọ Aládé Àlàáfíà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Bó O Ṣe Ń Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà 
- 10:55 Orin 103 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Ò Ní Kọ́ṣẹ́ Ogun Mọ́ 
- 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:05 Orin 79 
Ọ̀sán
- 1:20 Ohùn Orin 
- 1:30 Orin 76 
- 1:35 Ìrírí 
- 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:15 Àpínsọ Àsọyé: Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Máa Ń Ran Ara Wọn Lọ́wọ́ - • “Ẹ Ṣí Ọkàn Yín Sílẹ̀ Pátápátá” 
- • Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣe Púpọ̀ Sí I 
- • Máa Bọlá Fáwọn Àgbàlagbà 
 
- 3:00 Orin 57 àti Ìfilọ̀ 
- 3:10 Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Máa Ń Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi 
- 3:55 Orin 45 àti Àdúrà