“Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà”
ÒWÚRỌ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 9 àti Àdúrà 
- 10:00 “Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà, Kí Inú Yín sì Máa Dùn” 
- 10:15 O Lè Láyọ̀ Bó O Tiẹ̀ Ní Ìṣòro 
- 10:30 Ẹ Máa Ní ‘Ìdùnnú Tó Kún Rẹ́rẹ́’ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù 
- 10:55 Orin 76 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohunkóhun “Di Ẹrù Pa” Ọkàn Yín 
- 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:05 Orin 51