Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- 1. Báwo la ṣe lè “gbọ́ ohun tí ẹ̀mí ń sọ”? (Ìfi. 1:3, 10, 11; 3:19) 
- 2. Kí ló máa jẹ́ ká lè máa ṣiṣẹ́ kára, ká sì máa fara dà á nìṣó? (Ìfi. 2:4) 
- 3. Kí ló máa jẹ́ ká nígboyà ká sì múra sílẹ̀ de inúnibíni? (Òwe 29:25; Ìfi. 2:10, 11) 
- 4. Kí la lè ṣe tá ò fi ní sẹ́ ìgbàgbọ́ tá a ní nínú Jésù? (Ìfi. 2:12-16) 
- 5. Báwo la ṣe lè di ohun tí a ní mú ṣinṣin? (Ìfi. 2:24, 25; 3:1-3, 7, 8, 10, 11) 
- 6. Kí la lè ṣe tí ìtara wa ò fi ní dín kù? (Ìfi. 3:14-19; Mát. 6:25-27, 31-33) 
© 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-brpgm26-YR