“Gbọ́ Ohun Tí Ẹ̀mí Ń Sọ fún Àwọn Ìjọ”
Àárọ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 1 àti Àdúrà 
- 10:00 Báwo La Ṣe Lè “Gbọ́ Ohun Tí Ẹ̀mí Ń Sọ”? 
- 10:15 ‘Àárẹ̀ Ò Mú Ọ’ 
- 10:30 “Má bẹ̀rù” 
- 10:55 Orin 73 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 ‘O Ò Sẹ́ Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Mi’ 
- 11:35 Ìrìbọmi: Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Ṣèrìbọmi? 
- 12:05 Orin 79 
Ọ̀sán
- 1:20 Ohùn Orin 
- 1:30 Orin 126 
- 1:35 Ìrírí 
- 1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:15 Àpínsọ Àsọyé: Bá A Ṣe Lè Fi Ìmọ̀ràn Jésù Sílò - • “Ẹ Di Ohun Tí Ẹ Ní Mú Ṣinṣin” 
- • ‘Máa Ṣọ́ra, Kí O sì Fún Àwọn Ohun Tó Ṣẹ́ Kù Lókun’ 
- • “Mo Ti Ṣí Ilẹ̀kùn Sílẹ̀ Níwájú Rẹ” 
 
- 3:00 Orin 76 àti Ìfilọ̀ 
- 3:10 “Jẹ́ Onítara” 
- 3:55 Orin 129 àti Àdúrà