Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Ti Ọdún 2019
Àwọn Ìwé Tó Wà Lédè Yorùbá
“Jèhófà fúnra rẹ̀ ló ń fúnni ní ọgbọ́n; ẹnu rẹ̀ ni ìmọ̀ àti ìfòyemọ̀ ti ń wá”—Òwe 2:6
Àkíyèsí: A ti yí àwọn kan pa dà lára àwọn ìtọ́ni tó wà nínú ìwé àtijọ́.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ti Ọdún 2019
Àwọn Ìwé Tó Wà Lédè Yorùbá
A Tẹ̀ Ẹ́ ní September 2022
Yoruba (rsg19-YR)
© 2020, 2022 WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA