Ìlera Ara àti Ọpọlọ
Ìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Ń Ṣàìsàn Olùkọ́, orí 23
Ara Èèyàn
O Lè Túbọ̀ Máa Rántí Nǹkan! Jí!, 4/2009
Ọlọ́run ‘Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-tìyanu’ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2007
Ẹwà àti Ìrísí Ẹni
Ṣó Yẹ Kí N Máa Da Ara Mi Láàmú Torí Bí Mo Ṣe Rí? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 2
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ẹwà Jí!, No. 4 2016
Bí Àníyàn Nípa Ìrísí Ẹni Bá Gbani Lọ́kàn Ju Bó Ṣe Yẹ Lọ Jí!, 8/8/2004
Ẹ̀yà Ara àti Iṣẹ́ Tí Wọ́n Ń Ṣe
Ṣé “Ọpọlọ Méjì” La Ní? Jí!, No. 3 2017
Ìlera Ara
Ohun Tó Máa Mú Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I Jí!, 7/2015
Ohun 3—Má Ṣe Máa Jókòó Gẹlẹtẹ Sójú Kan
Ohun 4—Ṣọ́ra fún Ohun Tó Lè Ṣàkóbá fún Ìlera Rẹ
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Tọ́jú Ara Mi? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 10
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Tọ́jú Ara Mi? Jí!, 7/2010
Ipò Rẹ Nípa Tẹ̀mí àti Ìlera Rẹ Ilé Ìṣọ́, 2/1/2004
Ọ̀nà 6 Tí O Lè Gbà Dáàbò Bo Ìlera Rẹ Jí!, 10/8/2003
Àwọn Nǹkan Tó Lè Nípa Lórí Ìlera Rẹ Jí!, 9/8/2003
Ìmọ́tótó
Kí Nìdí Tí Ìmọ́tótó Fi Ṣe Pàtàkì? Ilé Ìṣọ́, 12/1/2008
Ọṣẹ—“Abẹ́rẹ́ Àjẹsára” Tó O Lè Gún Fúnra Rẹ Jí!, 12/8/2003
Eré Ìmárale
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fi Ìrìn Rírìn Ṣe Eré Ìmárale? Jí!, 3/8/2004
Yoga—Ṣé Eré Ìmárale Lásán Ni àbí Nǹkan Mí ì Wà Ńbẹ̀? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2002
Oúnjẹ
Ṣé Ààwẹ̀ Gbígbà Ló Máa Jẹ́ Kó O Sún Mọ́ Ọlọ́run? Ilé Ìṣọ́, 4/1/2009
Àwọn Ìṣòro Ńlá Tó Ń Fà Á àti Ibi Tí Àbájáde Rẹ̀ Nasẹ̀ Dé Jí!, 3/8/2003
Oúnjẹ Aṣaralóore Ń Bẹ Níkàáwọ́ Rẹ Jí!, 5/8/2002
Oorun
Àwọn Ọ̀dọ́langba Tó Máa Ń sùn Ṣáá—Ṣé Ọ̀ràn Wọn Ò Ń Fẹ́ Àmójútó Báyìí? Jí!, 9/8/2002
Ọgbọ́n Tó O Lè Dá sí Wàhálà
Ẹ̀rín Músẹ́—Ẹ̀bùn Tó O Lè Fúnni Jí!, No. 1 2017
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Wàhálà Níléèwé? Jí!, 10/2008
Oògùn Ajẹ́bíidán Fún Másùnmáwo Ilé Ìṣọ́, 12/15/2001
Ìtọ́jú Ìṣègùn
Wíwà ní Ìwọ̀ntúnwọ̀nsì
Jèhófà Yóò Gbé Ọ Ró Ilé Ìṣọ́, 12/15/2015
Túbọ̀ Sún Mọ́ Jèhófà (§ Ìlera) Ilé Ìṣọ́, 1/15/2013
Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Ìlànà Ìwé Mímọ́ Lórí Ọ̀rọ̀ Ìtọ́jú Ara Ilé Ìṣọ́, 11/15/2008
Ìtọ́jú Àfirọ́pò
‘Ẹ Pa Agbára Ìmòye Yín Mọ́ Délẹ̀délẹ̀’ (§ Bá A Ṣe Lè Bójú Tó Ọ̀ràn Àìlera) Ilé Ìṣọ́, 3/1/2006
Ewé àti Egbò Ṣé O Lè Lò Ó fún Ìwòsàn? Jí!, 1/8/2004
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Jẹ́ Kí Wọ́n Mú Àwọn Níyè? Jí!, 7/8/2003
Ìlera Tó Sunwọ̀n—Ṣé Ìtọ́sọ́nà Tuntun Ni?
Àwọn Ìtọ́jú Àfirọ́pò—Ìdí Tó Fi Jẹ́ Pé Òun Lọ̀pọ̀ Èèyàn Ń Yíjú Sí
Àìsàn, Àrùn Ara àti Ti Ọpọlọ
A kọ àwọn àpilẹ̀kọ yìí láti sọ ohun tó ń lọ fún aráyé. Wọn kò sọ pé irú ìtọ́jú kan pàtó ló dára jù láti gbà. Torí náà, ó yẹ́ kí ẹnì kọ̀ọ̀kan fara balẹ̀ gbé oríṣiríṣi ìtọ́jú tó wà yẹ̀ wò, kó sì ṣe ìpinnu tí kò ta ko àwọn ìlànà Bíbélì.
Ọ̀pọ̀ àwọn àpilẹ̀kọ yìí dá lórí ìtàn ìgbésí ayé àwọn ẹnì kan, ó sì lè jẹ́ ìṣírí fún àwọn mí ì tó ń kojú irú ìṣòro kan náà.
Kí Nìdí Tí Mo Fi Ń Ṣàìsàn Tó Báyìí? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 8
Bí Èèyàn Rẹ Kan Bá Lárùn Ọpọlọ Jí!, 10/8/2004
Ọjọ́ Pẹ́ Táráyé Ti Ń Gbógun Ti Àrùn Jí!, 6/8/2004
Àárẹ̀ Ọkàn Tàbí Àìsàn Tó Ń Múni Hùwà Lódìlódì
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn Jí!, No. 1 2017
Ojú Ìwòye Bíbélì: Ìsoríkọ́ Jí!, 11/2013
Sún Mọ́ Ọlọ́run: Ìtùnú fún Àwọn Tó Ní Ìbànújẹ́ Ọkàn Ilé Ìṣọ́, 6/1/2011
Má Bẹ̀rù Jèhófà Wà Pẹ̀lú Rẹ! Ilé Ìṣọ́, 5/1/2006
“Ẹ Kò Mọ Ohun Tí Ìwàláàyè Yín Yóò Jẹ́ Lọ́la” Ilé Ìṣọ́, 12/1/2000
Adití
Wo Èdè Àwọn Adití lábẹ́ Ẹ̀kọ́ Ìwé àti Èdè
Afọ́jú
Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà: Mo ti lè ran àwọn míì lọ́wọ́ báyìí Ilé Ìṣọ́, 10/1/2015
“Tí Kingsley Bá Lè Ṣe É, Èmi Náà Lè Ṣe É!” Ilé Ìṣọ́, 6/15/2015
Ran Àwọn Afọ́jú Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Mọ Jèhófà Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba, 5/2015
Ọlọ́run Fún Mi Ní ‘Ohun Tí Ọkàn Mi Ń Fẹ́’ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2005
Ìgbà Tí Mo Fọ́jú Lojú Mi Tó Là! Ilé Ìṣọ́, 5/1/2004
Bí Mo Tilẹ̀ Dití Tí Mo Tún Fọ́jú, Mo Rí Ààbò Jí!, 6/8/2001
Àìjẹunrekánú
Àìsàn Ikùn Ríro Ọmọdé
Kí Lo Lè Ṣe Bí Ọmọ Rẹ Bá Ń Ké Ṣáá? Jí!, 5/8/2004
Àìsàn Kò Gbóògùn Tí Kì Í Jẹ́ Kéèyàn Mí Dáadáa, Kí Oúnjẹ Dà Nínú (Cystic Fibrosis)
Ìgbàgbọ́ Rẹ̀ Fún Àwọn Ẹlòmíràn Níṣìírí Ilé Ìṣọ́, 7/1/2006
Àìsàn Tí Kì Í Jẹ́ Kí Egungun Lágbára (Osteogenesis Imperfecta)
Tí wọ́n tún ń pè ní àrùn brittle bone
Sísin Ọlọ́run Ni Oògùn Àìsàn Rẹ̀! Ilé Ìṣọ́, 11/15/2013
Ohun Tó Jẹ́ Kí N Máa Láyọ̀ Láìka Àìlera Mi Sí Ilé Ìṣọ́, 5/1/2009
Àìsàn Tí Kì Í Jẹ́ Kí Ọpọlọ Ṣiṣẹ́ Bó Ṣe Tọ́, Ìyẹn Down Syndrome
Àdánwò Mú Ká Túbọ̀ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Ilé Ìṣọ́, 4/15/2010
Àìsàn Tó Ń Jẹ́ Kí Lọ́fíńdà Gbòdì Lára (MCS)
Àìrí Oorun Sùn
Wo Oorun lábẹ́ Ìlera Ara àti Ọpọlọ lábẹ́ Ìlera Ara
Àjàkálẹ̀ Àrùn Black Death (Bubonic Plague)
Àjàkálẹ̀ Àrùn Black Death—Ó Gbo Yúróòpù ní Sànmánì Ìbẹ̀rẹ̀ Ọ̀làjú Jí!, 2/8/2000
Aláàbọ̀ Ara
Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Mi Ò Ní Apá Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 6 2016
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Bá Nílò Àbójútó Àrà Ọ̀tọ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2009
Onírúurú Nǹkan Ló Ń Sọni Di Aláàbọ̀ Ara Ilé Ìṣọ́, 5/1/2002
Àpọ̀jù Àníyàn Ṣíṣe
Bí Wọ́n Ṣe Borí Jìnnìjìnnì Tó Bá Wọn Nígbà Táwọn Apániláyà Yin Bọ́ǹbù Jí!, 2/8/2005
“Ẹ Kò Mọ Ohun Tí Ìwàláàyè Yín Yóò Jẹ́ Lọ́la” Ilé Ìṣọ́, 12/1/2000
Aràrá
Bí Wọn Ò Tiẹ̀ Ga, Wọ́n Lọ́kàn Tó Dára Ilé Ìṣọ́, 2/15/2000
Àrùn Àtọ̀gbẹ
Àrùn Bíburẹ́wà Lójú Ara Ẹni
Bí Àníyàn Nípa Ìrísí Ẹni Bá Gbani Lọ́kàn Ju Bó Ṣe Yẹ Lọ Jí!, 8/8/2004
Àrùn Chagas
Àwọn Àrùn Tí Kòkòrò Ń Gbé Kiri Ìṣòro Tí Ń Gbilẹ̀ Jí!, 6/8/2003
Àrùn Éèdì
Ìṣirò Nípa Àrùn Éèdì Ń Kóbànújẹ́ Ńláǹlà Báni! Jí!, 3/8/2001
Àwọn Ìyá Tó Ní Àrùn Éèdì Ko Ìṣòro Jí!, 1/8/2000
Àrùn Ẹsẹ̀ Rírinni Wìnnìwìnnì (RLS)
Ǹjẹ́ Ẹsẹ̀ Máa Ń Rìn Ọ́ Wìnnìwìnnì? Jí!, 12/8/2000
Àrùn Ẹ̀tẹ̀
Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Ṣé àrùn tí Bíbélì pè ní ẹ̀tẹ̀ náà làrùn tá a mọ̀ sí ẹ̀tẹ̀ lónìí?) Ilé Ìṣọ́, 2/1/2009
Àrùn Gágá
Àrùn Inú Ọpọlọ, Ìyẹn Cerebral Palsy
Ojú Jairo—Mú Kó Lè Sin Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 3/1/2015
Bí Loida Ṣe Di Ẹni Tó Ń Sọ̀rọ̀ Jí!, 9/8/2000
Àrùn Lyme
Kí Ló Dé Tí Wọ́n Tún Fi Ń Padà Wá? Jí!, 6/8/2003
Àrùn Oríkèé Ara Ríro
Àrùn Rọpárọsẹ̀
Jèhófà Fi Àánú Hàn sí Mi Ju Bí Mo Ṣe Rò Lọ Ilé Ìṣọ́, 8/1/2015
Àrùn Rọmọlápárọmọlẹ́sẹ̀ (Polio)
Mo Gbádùn ‘Ìgbésí Ayé Ìsinsìnyí’ Dé Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́! Ilé Ìṣọ́, 6/1/2005
Àrùn Tí Kòkòrò Ń Gbé Kiri
Àrùn Tó Máa Ń Mú Kí Ọ̀pá Ẹ̀yìn Là (Spina Bifida)
Jèhófà ‘Ń Bá Mi Gbé Ẹrù Mi Lójoojúmọ́’ Ilé Ìṣọ́, 8/15/2013
Àrùn Tó Ń Dégbò Sára Ìtẹ́nú Ìwọ́rọ́kù (Ulcerative Colitis)
Bí Ìgbàgbọ́ Ṣe Ran Ìdílé Kan Lọ́wọ́ Nígbà Ìpọ́njú Jí!, 5/8/2004
Àrùn Tó Ń Múni Ṣarán (Alzheimer’s)
“Ó Lè Jẹ́ Orin Ló Máa Ṣèrànwọ́” Jí!, 10/2010
Ó Rán An Létí Àwọn Nǹkan Tó Nífẹ̀ẹ́ Sí Jí!, 12/8/2005
Àrùn Wárápá
Mo Pinnu Pé Mo Gbọ́dọ̀ Bá Ohun Tí Mò Ń Lé Jí!, 7/8/2005
Dídákú
Kí Ló Fà Á Tí Mo FI Máa Ń Dákú? Jí!, 4/2007
Dídọ́gbẹ́ Síra Ẹni Lára
Àwọn Ìṣòro Wo Ló Ń Bá Àwọn Ọ̀dọ́ Fínra? (Àpótí: Dídọ́gbẹ́ Síra Ẹni Lára) Jí!, 10/2009
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dẹ́kun Dídọ́gbẹ́ Síra Mi Lára? Jí!, 4/2006
Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tí Mo Fi Ń Dọ́gbẹ́ Síra Mi Lára? Jí!, 1/2006
Ẹ̀jẹ̀ Ríru
Ẹ̀jẹ̀ Ríru—Bá A Ṣe Lè Dènà Rẹ̀ àti Bá A Ṣe Lè Kápá Rẹ̀ Jí!, 5/8/2002
Ibà
Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Àìsàn Ibà Jí!, 9/2015
Bí Àìsàn Ibà Bá Ń Ṣe Ọmọ Rẹ Jí!, 12/8/2003
Ìṣòro Àìfẹ́ Máa Jẹun Dáadáa
Ewu Tó Wà Nínú Oge Àṣejù Jí!, 9/8/2003
Nǹkan Tí Kò Báni Lára Mu
Oúnjẹ Tó Gbòdì Lára Àtèyí Tí Kò Báni Lára Mu—Ṣó Yàtọ̀ Síra? Jí!, No. 3 2016
Kí Ló Dé Tí Ọ̀f ìnkìn Tí Nǹkan Tó Ń Kù Ń Fà Fi Ń Yọ Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́nu? Jí!, 6/8/2004
Oúnjẹ Tí Kò Báni Lára Mu
Oúnjẹ Tó Gbòdì Lára Àtèyí Tí Kò Báni Lára Mu—Ṣó Yàtọ̀ Síra? Jí!, No. 3 2016
Rorẹ́
‘Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ sí Mi Yìí?’ Jí!, 7/8/2004
Sísanra Jọ̀kọ̀tọ̀
Ṣé Ìṣòro Ni Pé Kéèyàn Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀?
Kí Ló Ń Jẹ́ Kéèyàn Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀?
Kí Lẹni Tó Bá Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀ Lè Rí Ṣe Sí I?
Ǹjẹ́ Àǹfààní Kankan Wà Nínú Kéèyàn Dín Bó Ṣe Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀ Kù?
Oyún, Ọmọ Bíbí àti Ìtọ́jú Ìkókó
Ìgbìmọ̀ Alárinà Ilé Ìwòsàn lè fún àwọn dókítà ní ìwé kan tó ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé tó máa ràn wọ́n lọ́wọ́ nípa ìtọ́jú nǹkan wọ̀nyí. Orúkọ ìwé náà ni Clinical Strategies for Avoiding and Controlling Hemorrhage and Anemia Without Blood Transfusion in Obstetrics and Gynecology. Kàn sí àwọn alàgbà ìjọ rẹ fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé.
Ìtàn Àtijọ́: Ignaz Semmelweis Jí!, No. 3 2016
Bí Ọmọ Ṣe Ń Yí Nǹkan Pa Dà Láàárín Tọkọtaya Ìdílé Aláyọ̀, apá 6
Àmujù Ọtí Lè Kó Bá Ìlera Rẹ Jí!, 10/8/2005
Bó O Ṣe Lè Túbọ̀ Dáàbò Bo Oyún Rẹ Jí!, 1/8/2003
Ọjọ́ Ogbó
Tún wo Àwọn Àgbàlagbà lábẹ́ Ìgbésí Ayé Kristẹni lábẹ́ Bá A Ṣe Ń Ti Àwọn Ará Wa Lẹ́yìn
Bó O Ṣe Lè Dàgbà Lọ́nà Tó Ń Yẹni Ilé Ìṣọ́, 6/1/2015
Ohun Tó Lè Dáàbò Bo Àwọn Àgbàlagbà Jí!, 4/2011
Kí Nìdí Tá A Fi Ń Darúgbó? Jí!, 7/2006
Ojú Tí Wọ́n Fi Ń Wo Àwọn Arúgbó Ń Yí Padà Jí!, 9/8/2001
Dídàgbà Pọ̀ Ayọ̀ Ìdílé, orí 14
Ẹni Tó Ń Tọ́jú Aláìsàn
Tí Àìsàn Gbẹ̀mí-Gbẹ̀mí Bá Ń Ṣe Ẹni Tá A Nífẹ̀ẹ́ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 4 2017
Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Èèyàn Rẹ Bá Ń Ṣàìsàn Jí!, 11/2015
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Bá Nílò Àbójútó Àrà Ọ̀tọ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2009
Ìdààmú Àwọn Dókítà Jí!, 2/8/2005
Nígbà Tí Mẹ́ḿbà Kan Nínú Ìdílé Bá Ń Ṣàìsàn Ayọ̀ Ìdílé, orí 10
Àṣà Tó Ti Di Bárakú
Wo Àṣà Tó Ti Di Bárakú lábẹ́ Ètò Àwọn Nǹkan Sátánì