ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rsg19
  • Ìṣekúṣe

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìṣekúṣe
  • Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ẹ̀dà Ti Ọdún—2019
  • Ìsọ̀rí
  • Ìbẹ́yà-kannáà-lòpọ̀
  • Fífọwọ́ Pa Ẹ̀yà Ìbímọ Ẹni
  • Àwòrán Oníhòòhò
  • Àwọn Ọ̀dọ́
Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ẹ̀dà Ti Ọdún—2019
rsg19

Ìṣekúṣe

Tún wo Panṣágà lábẹ́ Ìdílé lábẹ́ Àwọn Ìṣòro Ìdílé àti Ojútùú àti Ìwàkiwà lábẹ́ Ètò Àwọn Nǹkan Sátánì lábẹ́ Ẹ̀mí Ayé

Tó o bá fẹ́ wádìí nípa ìwà ọ̀daràn tó ní ìṣekúṣe nínú, wo Ìwà Ọ̀daràn àti Ìwà Ipá lábẹ́ Ètò Àwọn Nǹkan Sátánì

A Lè Jẹ́ Oníwà Mímọ́ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2015

Ojú Ìwòye Bíbélì: Panṣágà Jí!, 7/2015

❐ Ilé Ìṣọ́, 5/15/2015

Ṣọ́ra! Sátánì Fẹ́ Pa Ọ́ Jẹ

O Lè Bá Sátánì Jà Kó O sì Borí!

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó Jí!, 11/2013

❐ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2011

Ǹjẹ́ Ìdáhùn Ìbéèrè Yẹn Ṣe Pàtàkì?

Bíbélì Dáhùn Ìbéèrè Mẹ́wàá Nípa Ìbálòpọ̀

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbé Ìgbé Ayé Wa Ní Ìbámu Pẹ̀lú Àwọn Ìlànà Bíbélì?

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣó Dáa Kí Ọkùnrin àti Obìnrin Máa Gbé Pọ̀ Kí Wọ́n Tó Ṣègbéyàwó? Jí!, 1/2010

Ṣé Wàá Pa Ìwà Títọ́ Rẹ Mọ́? Ilé Ìṣọ́, 12/15/2008 ¶10

Ẹ Máa Wà Ní Mímọ́ Nínú Ìbẹ̀rù Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 5/15/2008

“Ẹ Máa Sá fún Àgbèrè” ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 9

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Bí Ìfẹ́ Bá Ti Wà, Kò Sóhun Tó Burú Nínú Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó? Jí!, 1/2007

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ a lè yọ ẹnì kan kúrò nínú ìjọ nítorí ìwà àìmọ́? Ilé Ìṣọ́, 7/15/2006

‘Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Rẹ?’ (§ Jẹ́ Kí Ìwà Tìrẹ Yàtọ̀; § Jẹ́ Oníwà Mímọ́) Ọjọ́ Jèhófà, orí 8

Jẹ́ Oníwà Mímọ́ Nípa Dídáàbò Bo Ọkàn Rẹ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2004

Báwo Ni Agbára Láti Ronú Ṣe Lè Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọ? Ilé Ìṣọ́, 8/15/2002

Ẹ Má Ṣe Di Olùgbọ́ Tí Ń Gbàgbé Ilé Ìṣọ́, 6/15/2001

Bíborí Àìpé Ẹ̀dá Ilé Ìṣọ́, 3/15/2001

“Pa Àwọn Àṣẹ Mi Mọ́ Kí O sì Máa Bá A Lọ Ní Wíwà Láàyè” Ilé Ìṣọ́, 11/15/2000

❐ Ilé Ìṣọ́, 11/1/2000

Ìwà Rere Ti Ń Dín Kù

Ṣé Ìwà Rere Tí Bíbélì Fi Kọ́ni Ló Dára Jù Lọ?

Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ìwà Mímọ́

O Lè Máa Bá Híhùwà Mímọ́ Nìṣó

Má Ba Ara Rẹ Lórúkọ Jẹ́ (§ “Má Ṣe Fẹ́ Ẹwà Ojú Rẹ̀”; § ‘Má Ṣe Wa Iná Jọ sí Oókan Àyà Rẹ’) Ilé Ìṣọ́, 9/15/2000

O Lè Jẹ́ Oníwà Mímọ́ Nínú Ayé Oníṣekúṣe Ilé Ìṣọ́, 7/15/2000

Ìbẹ́yà-kannáà-lòpọ̀

Ṣé Bíbélì Fàyè Gbà Á Pé Kí Ọkùnrin Fẹ́ Ọkùnrin? Jí!, No. 4 2016

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ìdí Kankan Wà Tí Ìbẹ́yà-kannáà-lòpọ̀ Fi Tọ̀nà? Jí!, 4/2012

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìbẹ́yà-Kannáà-Lòpọ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 23

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìbẹ́yà-kannáà-lòpọ̀? (Àpótí: Téèyàn Bá Ń Bá Tọkùnrin Tobìnrin Lò Pọ̀ Ńkọ́?) Jí!, 1/2011

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sá fún Bíbá Ọkùnrin Tàbí Obìnrin Bíi Tèmi Lò Pọ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 28

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sá fún Bíbẹ́yà Kan Náà Lò Pọ̀? Jí!, 4/2007

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ọlọ́run Fọwọ́ Sí Kí Ọkùnrin àti Ọkùnrin Máa Fẹ́ra? Jí!, 4/8/2005

Ojú Ìwòye Bíbélì: Gbígbé Ìgbésí Ayé Tó Yàtọ̀ sí Ti Ẹ̀dá​—⁠Ǹjẹ́ Ọlọ́run Fọwọ́ sí I? Jí!, 10/8/2003

Ẹ̀bi Ta Ni​—⁠Ṣé Ẹ̀bi Rẹ Ni àbí Ti Apilẹ̀ Àbùdá Rẹ? Ilé Ìṣọ́, 6/1/2002

Fífọwọ́ Pa Ẹ̀yà Ìbímọ Ẹni

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Fífọwọ́ Pa Ẹ̀yà Ìbímọ Mi? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 25

Jáwọ́ Nínú Fífọwọ́ Pa Ẹ̀yà Ìbímọ Rẹ ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ Àfikún

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Àṣà Búburú Yìí? Jí!, 1/2007

Àwòrán Oníhòòhò

O Lè Borí Ìdẹwò! Ilé Ìṣọ́, 4/1/2014

Àwòrán Oníhòòhò​—⁠Ó Léwu Àbí Kò Léwu? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2013

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ a lè yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́ nítorí wíwo ohun tó ń mú ọkàn èèyàn fà sí ìṣekúṣe? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2012

Ǹjẹ́ O Kórìíra Ìwà Àìlófin? Ilé Ìṣọ́, 2/15/2011 ¶10

Má Ṣe Máa Wo Àwọn Ohun Tí Kò Ní Láárí! Ilé Ìṣọ́, 4/15/2010 ¶9 sí 11

Jẹ́ “Onítara fún Iṣẹ́ Àtàtà”! (§ Máa Fìtara Gba Ìkìlọ̀) Ilé Ìṣọ́, 6/15/2009

Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀: Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Máa Ṣera Wọn Lọ́kan Ilé Ìṣọ́, 11/1/2008

“Ẹ Máa Sá fún Àgbèrè” (§ Ibi Ṣíṣe Àwọn Ohun Tó Ń Mọ́kàn Fà Sí Ìṣekúṣe Ni Àgbèrè Ti Ń Bẹ̀rẹ̀) ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ orí 9

Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí N Máa Wo Àwòrán Oníhòòhò? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 33

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Wíwo Àwòrán Oníhòòhò? Jí!, 1/2008

Bíbélì Jẹ́ Ká Mọ Bí Ìwà Ibi Ṣe Bẹ̀rẹ̀! (§ “Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọkàn-Àyà Rẹ”) Ilé Ìṣọ́, 6/1/2007

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ a lè yọ ẹnì kan kúrò nínú ìjọ Ọlọ́run nítorí ìwà àìmọ́? Ilé Ìṣọ́, 7/15/2006

❐ Jí!, 8/8/2003

Èrò Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Tí Àwọn Èèyàn Ní Nípa Àwọn Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè

Kí Nìdí Tí Àwọn Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè Fi Gbilẹ̀ Tó Bẹ́ẹ̀?

Ìpalára Tí Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè Ń Ṣe

Ojú Ìwòye Bíbélì: Àwọn Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè​—⁠Ṣé Nǹkan Ṣeréṣeré Lásán Ni Wọ́n? Jí!, 7/8/2002

“Ewu Tó Dojú Kọ Ìlera Gbogbo Ènìyàn” Ilé Ìṣọ́, 4/15/2001

Àwọn Ọ̀dọ́

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Fi Ìbálòpọ̀ Lọ̀ Mí? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 7

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìfipá-Báni-Lòpọ̀? Ìbéèrè 10, ìbéèrè 8

Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé: Bá Ọmọ Rẹ Sọ̀rọ̀ Nípa Fífi Ọ̀rọ̀ Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Fóònù Jí!, 1/2014

Ṣé Ìbálòpọ̀ Máa Jẹ́ Ká Túbọ̀ Fẹ́ràn Ara Wa? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 24

Ṣé Ó Burú Bí Ọkùnrin àti Obìnrin Bá Kàn Gbé Ara Wọn Sùn? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 26

Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Kó Sọ́wọ́ Àwọn Tó Ń Fipá Báni Lò Pọ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní, orí 32

Bí Àwọn Ọ̀dọ́ Ṣe Lè Rí Ìrànlọ́wọ́ (§ Sá fún Ìṣekúṣe) Jí!, 10/2009

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Rántí Ẹlẹ́dàá Yín Atóbilọ́lá Nísinsìnyí (§ Wọ́n Di Aláìṣòótọ́ Nígbà Tó Kù Díẹ̀ Kí Wọ́n Wọ Ilẹ̀ Ìlérí) Ilé Ìṣọ́, 4/15/2008

Ìgbà Wo Ló Dàṣejù? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 4

Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí N Ní Ìbálòpọ̀ Kí N Tó Ṣègbéyàwó? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 5

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbọ́kàn Mi Kúrò Lórí Ìbálòpọ̀? Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, orí 29

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Bí Ọkùnrin Tàbí Obìnrin Kan Bá Ní Kí N Jẹ́ Ká Jọ Gbéra Wa Sùn Ńkọ́? Jí!, 4/2007

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Máa Bá Wọn Dá sí Ọ̀ràn Ìbálòpọ̀ Nílé Ìwé? Jí!, 4/2006

Oyún Ọ̀dọ́langba Ìṣòro Tó Kárí Ayé Jí!, 10/8/2004

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó? Jí!, 9/8/2004

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Ní Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó? Jí!, 8/8/2004

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Kí Nìdí Tí Jíjíròrò Nípa Ìbálòpọ̀ Lórí Tẹlifóònù Fi Burú? Jí!, 3/8/2004

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé: Ṣé Kéèyàn Bímọ​—⁠La Fi Ń Mọ̀ Pọ́kùnrin Ni? Jí!, 5/8/2000

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́