Owurọ Kan Ti O Parọ́rọ́
Ohun ti onkawe kan ni Illinois, U.S.A., wi niyẹn pe iwe-irohin Ji! npese. Ẹni naa kọwe pe, “a ya mi lẹnu lọna ti ntẹnilọrun lẹhin kika ẹda itẹjade Ji! yin.” Iwe-irohin naa ni a fun mi nipasẹ obinrin kan ti o wa ni ibudokọ rélùwéè ni owurọ yii. O mu ki nnimọlara itura ati alaafia, o si jẹ eyi ti o kun fun isọfunni gan an. Ẹ jọwọ jẹ ki nmọ bi mo ṣe le maa gba awọn ẹda itẹjade naa deedee.
“Ẹ ṣeun pupọ lẹẹkansi fun fifun mi laaye o kere tan owurọ kan ti o parọ́rọ́.”
Awa nimọlara pẹlu pe iwọ le janfaani lati inu awọn ọrọ ti nfani lọkan mọra ninu Ji! Bi iwọ yoo ba fẹ lati gba iwe-irohin yii, wulẹ kọ ọrọ kun alafo ti nbaa rin yii ki o si firanṣẹ.
Emi yoo fẹ ki a fi iwe-irohin Ji! ranṣẹ si ile mi. (Kọwe si adirẹsi ti nbẹ nisalẹ fun isọfunni.)