ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w08 4/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
  • Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
w08 4/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

April 15, 2008

Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:

May 26, 2008–June 1, 2008

Kọ “Àwọn Ohun Tí Kò Ní Láárí” Sílẹ̀

OJÚ ÌWÉ 3

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 48, 20

June 2-8, 2008

Jẹ́ Kí Ọlọ́run Máa Ṣamọ̀nà Rẹ Nínú Ohun Gbogbo

OJÚ ÌWÉ 7

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 131, 225

June 9-15, 2008

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Rántí Ẹlẹ́dàá Yín Atóbilọ́lá Nísinsìnyí

OJÚ ÌWÉ 12

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 157, 183

June 16-22, 2008

Ìgbéyàwó àti Ọmọ Bíbí Lákòókò Òpin Yìí

OJÚ ÌWÉ 16

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 24, 164

June 23-29, 2008

Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Gbé Ìgbé Ayé Rere?

OJÚ ÌWÉ 21

ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 214, 67

Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 3 sí 11

Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí á jẹ́ ká mọ “àwọn ohun tí kò ní láárí,” ìyẹn àwọn ohun tí kò ní jẹ́ ká lè fi gbogbo ọkàn wa sin Jèhófà. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí jẹ́ ká rí àwọn ohun tó lè dẹkùn mú wa láìfura, ó sì jẹ́ ká rí ọ̀pọ̀ ìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kí Jèhófà máa ṣamọ̀nà wa nínú ohun gbogbo.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 àti 4 OJÚ ÌWÉ 12 sí 20

Àkọ́kọ́ nínú àpilẹ̀kọ méjì yìí jẹ́ káwọn ọ̀dọ́ mọ bí Bíbélì ṣe lè ràn wọ́n lọ́wọ́ tí wọ́n bá fẹ́ ṣe àwọn ìpinnu tó ṣe pàtàkì láyé wọn. Àpilẹ̀kọ kejì fún àwọn ọ̀dọ́ ní ìtọ́sọ́nà tó bọ́gbọ́n mu látinú Ìwé Mímọ́ lórí ohun tí wọ́n gbọ́dọ̀ fi sọ́kàn tí wọ́n bá ń ronú àtiṣègbéyàwó tàbí tí wọ́n bá n ronú ọmọ bíbí.

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 5 OJÚ ÌWÉ 21 sí 5

Àpilẹ̀kọ tó kẹ́yìn ṣe àlàyé tó ń múni ronú jinlẹ̀ lórí ìwé Oníwàásù. Ó sọ àwọn nǹkan táwọn èèyàn kà sí pàtàkì láyé tá a wà yìí, ó tún wá sọ àwọn nǹkan tó ṣe pàtàkì jù lọ nígbèésí ayé àwa èèyàn.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:

Wọn Ò Sí Láàárín Wa àmọ́ A Kò Gbàgbé Wọn

OJÚ ÌWÉ 25

Ǹjẹ́ O Rántí

OJÚ ÌWÉ 29

Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè​—⁠Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jòhánù

OJÚ ÌWÉ 30

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́