Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 15, 2008
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
January 5-11
Ẹ Ṣèrànwọ́ Fáwọn Tó Ṣáko Lọ Kí Wọ́n Lè Pa Dà Sínú Agbo
OJÚ ÌWÉ 8
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 47, 101
January 12-18
Ẹ Ṣèrànwọ́ fún Wọn Kí Wọ́n Lè Tètè Pa Dà Láìjáfara!
OJÚ ÌWÉ 12
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 116, 184
January 19-25
Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Ìlànà Ìwé Mímọ́ Lórí Ọ̀rọ̀ Ìtọ́jú Ara
OJÚ ÌWÉ 23
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 44, 182
January 26–February 1
“Ẹ Kọ Ojú Ìjà sí Èṣù” bí Jésù Ti Ṣe
OJÚ ÌWÉ 27
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 174, 191
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá a Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 8 sí 16
Kọ́ nípa bí àwọn alàgbà àtàwọn ará ìjọ ṣe lè ṣèrànwọ́ fáwọn akéde tó ti ṣáko lọ kúrò nínú agbo Ọlọ́run. Àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí ṣàlàyé ọ̀nà tó o lè gbà ṣèrànwọ́ fáwọn akéde tó di aláìṣiṣẹ́mọ́. Sì tún kíyè sí báwọn ará ìjọ ṣe máa ń tẹ́wọ́ gba àwọn tó bá pa dà sínú ètò Ọlọ́run.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 23 sí 27
Kò burú tá a bá ń ṣàníyàn níwọ̀nba nípa ìlera wa. Nítorí náà, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń gba ìtọ́jú nílé ìwòsàn, oríṣi àwọn ìtọ́jú mìíràn sì wà tá ò lòdì sí. Àmọ́ ṣá o, ó ṣe pàtàkì pé kéèyàn ní ‘èrò inú tó yè kooro.’ (Títù 2:12) Ju gbogbo ẹ̀ lọ, ó yẹ ká máa bójú tó ìlera wa nípa tẹ̀mí kí àjọṣe tó wà láàárín àwa àti Ọlọ́run lè túbọ̀ dára sí i.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 27 sí 31
Kọ́ nípa bí Jésù ṣe fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ kíkọjú ìjà sí Èṣù. Àpilẹ̀kọ yìí jẹ́ ká rí ìdí tí Ọlọ́run fi fọkàn tán Ọmọ rẹ̀. Ó jẹ́ ká rí bí Jésù ṣe kọjú ìjà sí Èṣù tó sì borí ó sì tún jẹ́ ká rí bí àwa náà ṣe lè ṣe bẹ́ẹ̀.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
OJÚ ÌWÉ 3
Gbogbo Wọn Ń Fi “Ọkàn Kan” Sin Ọlọ́run
OJÚ ÌWÉ 6
“Máa Lépa Àwọn Ohun Tí Ń Yọrí sí Àlàáfíà”
OJÚ ÌWÉ 17
Ọ̀rọ̀ Jèhófà Yè—Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jákọ́bù, Ìwé Pétérù Kìíní àti Pétérù Kejì
OJÚ ÌWÉ 20
“Ìwé Orin Òkun”—Ìwé Tí Wọ́n Kọ Láàárín Àkókò Méjì Kan
OJÚ ÌWÉ 32