Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
July 6-12
Máa Tẹ̀ Síwájú sí Ìdàgbàdénú Torí Pé “Ọjọ́ Ńlá Jèhófà Sún Mọ́lé”
OJÚ ÌWÉ 9
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 123, 174
July 13-19
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Jẹ́ Kí Ìtẹ̀síwájú Yín Fara Hàn Kedere
OJÚ ÌWÉ 13
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 42, 56
July 20-26
Àwọn Áńgẹ́lì Jẹ́ “Ẹ̀mí fún Iṣẹ́ Ìsìn Gbogbo Ènìyàn”
OJÚ ÌWÉ 21
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 6, 5
July 27–August 2
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Tẹ̀ Lé “Kristi”?
OJÚ ÌWÉ 28
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 121, 134
Ohun Táwọn Àpilẹ̀kọ Tá A Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Dá Lé
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 àti 2 OJÚ ÌWÉ 9 sí 17
Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ dá lórí ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé kéèyàn dàgbà nípa tẹ̀mí àti bá a ṣe lè dẹni tó dàgbà nípa tẹ̀mí. Àpilẹ̀kọ kejì ṣàlàyé báwọn Kristẹni ọ̀dọ́ ṣe lè ṣe àwọn ìpinnu tó tọ́ nígbà tí wọ́n bá ń kojú àwọn ìṣòro ìgbà ọ̀dọ́ kí wọ́n bàa lè dẹni tó dàgbà nípa tẹ̀mí.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 21 sí 25
Bá a bá ń ṣàyẹ̀wò Ìwé Mímọ́, a lè rí bí àwọn áńgẹ́lì ṣe ń ṣe ojúṣe wọn gẹ́gẹ́ bí “ẹ̀mí fún iṣẹ́ ìsìn gbogbo ènìyàn.” Àpilẹ̀kọ yìí sọ ohun tí wọ́n ń ṣe láti ṣèránwọ́ fáwọn Kristẹni lónìí. Ó tún sọ ohun tá a lè rí kọ́ látara àwọn áńgẹ́lì olóòótọ́.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 28 sí 32
Jésù Kristi rọ àwọn olùgbọ́ ẹ̀ pé kí wọ́n máa tẹ̀ lé òun nígbà gbogbo. Àpilẹ̀kọ yìí jíròrò ìdí márùn-ún tó fi yẹ ká fẹ́ láti máa tẹ̀ lé “Kristi” àti bá a ṣe lè túbọ̀ máa ṣe bẹ́ẹ̀.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
OJÚ ÌWÉ 3
Ibo Ló Yẹ Kó O Wà Nígbà Tí Òpin Bá Dé?
OJÚ ÌWÉ 6
OJÚ ÌWÉ 18
Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìfẹ́ Kristi!
OJÚ ÌWÉ 19
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìdúróṣinṣin Ítítáì
OJÚ ÌWÉ 26