Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 15, 2009
Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ Ọ̀SẸ̀:
October 26–November 1
OJÚ ÌWÉ 7
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 62, 66
November 2-8
Jẹ́ Onígbọràn àti Onígboyà Bíi Kristi
OJÚ ÌWÉ 11
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 8, 107
November 9-15
OJÚ ÌWÉ 16
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 89, 35
November 16-22
Ohun Tó Mú Kí Ẹ̀kọ́ Tí Ọlọ́run Ń Kọ́ Wa Ta Yọ
OJÚ ÌWÉ 21
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 91, 59
November 23-29
Ǹjẹ́ O Mọyì Ohun Tí Jèhófà Ṣe Láti Dá Ọ Nídè?
OJÚ ÌWÉ 25
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ: 55, 153
OHUN TÁWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ DÁ LÉ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 1 sí 3 OJÚ ÌWÉ 7 sí 20
A mọ̀ pé ọ̀pọ̀ ọ̀nà ni Jésù gbà jẹ́ àwòfiṣàpẹẹrẹ fáwa Kristẹni. Àwọn àpilẹ̀kọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí dá lórí ìwà Jésù àtàwọn ohun tó ṣe. Wàá rí àwọn àpẹẹrẹ tó o lè máa tẹ̀ lé nínú ìdílé rẹ, nínú ìjọ àti nígbà tó o bá dojú kọ ìṣòro.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 21 sí 25
Báwo lo ṣe mọyì ẹ̀kọ́ òtítọ́ tó o ti kọ́ látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tó? Àpilẹ̀kọ yìí yóò ràn wá lọ́wọ́ láti ronú lórí àwọn àǹfààní àgbàyanu tó ń wá látinú ẹ̀kọ́ tí Ọlọ́run ń kọ́ wa. Ó tún jíròrò àwọn ìbùkún tá à ń rí gbà tá a bá yááfì nǹkan kan nítorí ìhìn rere.
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 5 OJÚ ÌWÉ 25 sí 29
Kí ni Jèhófà ṣe ká bàa lè rí ìdáǹdè kúrò lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú? Kí ló ná an? Tá a bá mọ ìdáhùn sáwọn ìbéèrè yìí, ìyẹn á jẹ́ ká fi ìmọrírì àtọkànwá hàn fún Jèhófà, yóò sì jẹ́ ká lè fi han Jèhófà bá a ṣe mọyì ìrètí ìdáǹdè tóun àti Ọmọ rẹ̀ jẹ́ ká ní.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ:
Ṣé Àwọn Òbí Mi—Ni Yóò Pinnu Ẹ̀sìn Mi Àbí Èmi Fúnra Mi?
OJÚ ÌWÉ 3
Mo Rí Ohun Rere Gbé Ṣe Nígbèésí Ayé Mi
OJÚ ÌWÉ 30