Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2012
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
- Àlàáfíà Yóò Wà fún Ẹgbẹ̀rún Ọdún àti Títí Láé! 9/15 
- Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Bọ̀wọ̀ fún Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, 1/15 
- Àwọn “Olùgbé fún Ìgbà Díẹ̀” Ń Sin Jèhófà ní Ìṣọ̀kan, 12/15 
- Àwọn Tó Wà Nínú Ìdílé Tí Wọ́n Ti Ń Ṣe Ẹ̀sìn Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Lè Láyọ̀, 2/15 
- Bá A Ṣe Lè Máa Fi Ìgboyà Kojú Ìpọ́njú Lóde Òní, 10/15 
- Bá A Ṣe Lè Máa Rúbọ sí Jèhófà Tọkàntọkàn, 1/15 
- Bí Ayé Yìí Ṣe Máa Dópin, 9/15 
- Ẹ Dúró Gbọn-in Kẹ́ Ẹ sì Sá fún Àwọn Ohun Tí Sátánì Fi Ń Múni, 8/15 
- Ẹ Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Rere Gbilẹ̀ Nínú Ìjọ, 2/15 
- “Ẹ Kò Mọ Ọjọ́ Tàbí Wákàtí Náà,” 9/15 
- Ẹ Má Ṣe Wo “Àwọn Ohun Tí Ń Bẹ Lẹ́yìn,” 3/15 
- Ẹ Máa Bá A Nìṣó Gẹ́gẹ́ Bí Ọmọ Ìjọba Ọlọ́run! 8/15 
- Ẹ Máa Dárí Ji Ara Yín Fàlàlà, 11/15 
- Ẹ Wà Lójúfò Bíi Ti Jésù, 2/15 
- Ẹgbẹ́ Àlùfáà Aládé Tó Máa Ṣe Gbogbo Aráyé Láǹfààní, 1/15 
- ‘Ẹ̀mí Mímọ́ Darí Wọn,’ 6/15 
- Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà—Ọlọ́run “Ìgbà àti Àsìkò,” 5/15 
- Ìríjú Tó Ṣeé Fọkàn Tán Ni Ẹ́! 12/15 
- Irú Ẹ̀mí Wo Lò Ń Fi Hàn? 10/15 
- Ìwà Ọ̀dàlẹ̀—Àmì Búburú Kan Tó Fi Hàn Pé À Ń Gbé ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn! 4/15 
- “Jèhófà Kan Ṣoṣo” Ń Kó Ìdílé Rẹ̀ Jọ, 7/15 
- Jèhófà Mọ Bó Ṣe Máa Dá Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Nídè, 4/15 
- Jèhófà Ń Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Wa Ká Lè Rí Ìgbàlà, 4/15 
- Jèhófà Ń Kó Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Aláyọ̀ Jọ, 9/15 
- Jèhófà Ni “Olùṣí Àwọn Àṣírí Payá,” 6/15 
- Jèhófà Ṣí Àwọn Ohun Tí Ó “Gbọ́dọ̀ Ṣẹlẹ̀ Láìpẹ́” Payá, 6/15 
- Jésù Kọ́ Wa Láti Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀, 11/15 
- Jẹ́ Kí Bẹ́ẹ̀ Ni Rẹ Jẹ́ Bẹ́ẹ̀ Ní, 10/15 
- Jẹ́ Kí Ìrètí Tá A Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀, 3/15 
- Jẹ́ Kí Jèhófà Ṣamọ̀nà Rẹ Síbi Tí Ojúlówó Òmìnira Wà, 7/15 
- “Jẹ́ Onígboyà àti Alágbára Gidigidi,” 2/15 
- Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú ‘Kókó Òtítọ́,’ 1/15 
- Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Sùúrù Jèhófà àti Jésù, 9/15 
- Kí Lo Gbọ́dọ̀ Ṣe Tó O Bá Fẹ́ Kí Jèhófà Dárí Jì Ẹ́? 11/15 
- Kí Ló Ń Mú Káyé Yẹni, 12/15 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Fi Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà sí Ipò Àkọ́kọ́? 6/15 
- Kọ́ Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́nà Látinú Àpẹẹrẹ Àwọn Àpọ́sítélì Jésù, 1/15 
- “Kọ́ Mi Láti Ṣe Ìfẹ́ Rẹ,” 11/15 
- Má Sọ̀rètí Nù Bí Ìgbéyàwó Rẹ Kò Bá Fún Ẹ Láyọ̀, 5/15 
- Máa Fi Ọkàn-Àyà Pípé Sin Jèhófà, 4/15 
- Máa Fi Sọ́kàn Pé Iṣẹ́ Ìwàásù Jẹ́ Kánjúkánjú, 3/15 
- Máa Hùwà Bí Ẹni Tó Kéré Jù, 11/15 
- Máa Sin Ọlọ́run Tí Ń Sọni Di Òmìnira, 7/15 
- “Mo Wà Pẹ̀lú Yín,” 8/15 
- Ǹjẹ́ Ò Ń Gbé Ògo Jèhófà Yọ? 5/15 
- “Olùgbé fún Ìgbà Díẹ̀” Ni Wá, 12/15 
- ‘Ọmọ Fẹ́ Láti Ṣí Baba Payá,’ 4/15 
- Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè “Jí Lójú Oorun,” 3/15 
- Ṣé Òótọ́ Lo Mọrírì Ìgbéyàwó Tó Jẹ́ Ẹ̀bùn Ọlọ́run? 5/15 
- Ṣègbọràn sí Ọlọ́run Kí O sì Jàǹfààní Nínú Àwọn Ìlérí Tó Fi Ìbúra Ṣe, 10/15 
- Ṣọ́ra fún Àwọn Ìdẹkùn Èṣù, 8/15 
- “Ta Ni Èmi Yóò Ní Ìbẹ̀rùbojo Fún?” 7/15 
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
- Ààlà Orílẹ̀-Èdè Kò Ṣèdíwọ́ (Potogí, Sípéènì, Faransé), 1/1 
- Àpéjọ Àgbègbè ‘Máa Ṣọ́ Ọkàn Rẹ!’ 5/1 
- Arìnrìn-Àjò Ìsìn, 8/15 
- Àṣẹ́kùsílẹ̀ Dí Àìní Tó Pọ̀ (ọrẹ), 11/15 
- Àwọn Apínwèé-Ìsìn-Kiri, 5/15 
- Àwọn Èèyàn Aztec Òde Òní, 3/1 
- Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Ètò Ọlọ́run, 9/15 
- Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 2/1, 8/1 
- Bá A Ṣe Ń Tọ́jú Àwọn Ohun Tá A Ti Lò Látijọ́, 1/15 
- ‘Báwo Ni Màá Ṣe Lè Wàásù?’ (alárùn rọpárọsẹ̀), 1/15 
- “Bí Mo Ṣe Fẹ́ Kó Rí Bẹ́ẹ̀ Náà Ló Rí” (iṣẹ́ aṣáájú-ọ̀nà), 7/15 
- Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ (Ilé Ìṣọ́), 1/15 
- Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Gbèjà Ẹ̀tọ́ Ẹni Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ̀ Kò Jẹ́ Kó Ṣiṣẹ́ Ológun (V. Bayatyan), 11/1 
- Ilé Ìṣọ́ Tá A Fi Èdè Gẹ̀ẹ́sì Tó Rọrùn Kọ, 12/15 
- Inú Rere Yí Ìwà Kíkorò Pa Dà, 6/15 
- Ìpàdé Ọdọọdún, 8/15 
- ‘Ìwàásù Tí Wọn Kò Gbọ́ Irú Rẹ̀ Rí’ (ilé iṣẹ́ rédíò Kánádà), 11/15 
- ‘Jọ̀wọ́, Yà Wá Ní Fọ́tò’ (Mẹ́síkò), 3/15 
- Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Wàásù Láti Ilé dé Ilé? 6/1 
- “Láti Ẹnu Àwọn Ọmọdé” (Rọ́ṣíà, Ọsirélíà), 10/15 
- Lẹ́tà Kan Láti . . . , 3/1, 6/1, 9/1, 12/1 
- Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Àwọn Obìnrin Tó Jẹ́ Òjíṣẹ́ Ọlọ́run? 9/1 
- ‘Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀, Ẹ Fi Ṣàríkọ́gbọ́n’ (Estonia), 12/1 
- Wọ́n Fi Ìgboyà Polongo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run! 2/15 
- ‘Wọ́n Ń Fi Mí Ṣe Ìran Wò’ (Àpótí ìwé tó ní táyà lẹ́sẹ̀), 2/15 
- Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú ní Brazil, 10/15 
- Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú ní Ecuador, 7/15 
BÍBÉLÌ
- Abala Àwọn Ọ̀dọ́, 1/1, 4/1, 7/1, 10/1 
- Bíbélì Lédè Gẹ̀ẹ́sì (ti Coverdale), 6/1 
- Èdè Swahili, 9/1 
- Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà, 1/1, 2/1, 4/1, 5/1, 7/1, 8/1, 10/1, 11/1 
- Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Ọjọ́ Ọ̀la, 1/1 
- Ṣé Òótọ́ Ni Bíbélì Ní Agbára Àràmàǹdà? 12/15 
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
- Báwo Lo Ṣe Ń Fúnni Ní Ìmọ̀ràn? 3/15 
- Bí Ọmọ Rẹ Tó Ti Bàlágà Bá Ń Ṣiyè Méjì Nípa Ẹ̀sìn Rẹ, 2/1 
- “Ẹ Ṣọ́ra fún Ìwúkàrà Àwọn Farisí,” 5/15 
- Gbèsè, 11/1 
- Inú Rere, 9/1 
- Ìwé Àdéhùn, 12/15 
- Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, 2/1, 5/1, 8/1, 11/1 
- Kí Nìdí Tí Àwọn Kristẹni Fi Ń Ṣe Ìrìbọmi? 4/1 
- Kọ́ Ọmọ Rẹ, 3/1, 6/1, 9/1, 12/1 
- Láti Má Ṣe Ní Ọkọ Tàbí Aya, 11/15 
- Máa Wá “Ìdarí Jíjáfáfá,” 6/15 
- Mú Kí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Gbádùn Mọ́ Ẹ Kó sì Ṣe Ẹ́ Láǹfààní, 1/15 
- Ǹjẹ́ Àwọn Tó Kọ́kọ́ Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀sìn Kristẹni Lọ́wọ́ Nínú Ìṣèlú? 5/1 
- Ǹjẹ́ Wíwò Tí Kristẹni Kan Ń Wo Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Fà sí Ìṣekúṣe Lè Burú Débi Tí Wọ́n Fi Lè Yọ Ọ́ Lẹ́gbẹ́? 3/15 
- Ṣé Ó Dìgbà Téèyàn Bá Lọ́kọ Tàbí Téèyàn Bá Láya Kó Tó Lè Láyọ̀? 10/1 
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
- Àádọ́rin Ọdún Rèé Tí Mo Ti Ń Di Ibi Gbígbárìyẹ̀ Lára Aṣọ Ẹni Tí Í Ṣe Júù Mú (L. Smith), 4/1 
- “Adùn Ń Bẹ ní Ọwọ́ Ọ̀tún Rẹ Títí Láé” (L. Didur), 3/15 
- “Àṣírí” Tí A Kọ́ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Mímọ́ (O. Randriamora), 6/15 
- Jèhófà Kọ́ Mi Láti Ṣe Ìfẹ́ Rẹ̀ (M. Lloyd), 7/15 
- Mo Di Òmìnira! (M. Kilin), 12/1 
- Mo Sún Mọ́ Àwọn Àgbàlagbà Tí Wọ́n Jẹ́ Ọlọgbọ́n (E. Gjerde), 5/15 
- Mo Ti Wá Mọ Ọlọ́run Tí Mo Ń Sìn Wàyí (M. Bacudio), 9/1 
- Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ran Agbo Ilé Kan Tó Ń Ṣe Ẹ̀sìn Híńdù Lọ́wọ́ (N. Govindsamy), 10/1 
- Ṣọ̀rẹ́ Láti Ọgọ́ta Ọdún (L. Turner, W. Kasten, R. Kelsey, R. Templeton), 10/15 
JÈHÓFÀ
- Baba, 7/1 
- Ìbéèrè Wo Lo Máa Fẹ́ Bi Ọlọ́run? 11/1 
- Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ní Ètò Kan? 2/1 
- Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Rán Jésù Wá sí Ayé? 12/1 
- Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Sọ Pé Kí Ábúráhámù Fi Ọmọ Rẹ̀ Rúbọ? 1/1 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Lo Orúkọ Ọlọ́run? 6/1 
- Ǹjẹ́ Ọlọ́run Yóò Fún Wa Ní Ìjọba Kan Tó Máa Ṣàkóso Gbogbo Ayé? 11/1 
- Olùgbọ́ Àdúrà, 7/1 
- Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Jẹ Ọlọ́run Lógún, 9/1 
- Sún Mọ́ Ọlọ́run, 1/1, 2/1, 3/1, 4/1, 5/1, 6/1, 7/1, 8/1, 9/1, 10/1, 11/1, 12/1 
- Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Dá Àwọn Èèyàn Lóró Nínú Iná Ọ̀run Àpáàdì? 10/1 
JÉSÙ KRISTI
- Àwọn Ìwé Ìhìn Rere ti Àpókírífà, 4/1 
- Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Ṣe Ìrántí Ikú Jésù? 3/1 
- Ẹ̀ṣẹ̀ Àwọn Ọ̀daràn Tí Wọ́n Kàn Mọ́gi Lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jésù, 2/1 
- Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè, 4/1 
- Ìgbà Wo Ni Jésù Di Ọba? 8/1 
- Kí Ni Jésù Ní Lọ́kàn Nígbà Tó Ní Kéèyàn Dé Ibùsọ̀ Kejì? (Mt 5:41), 4/1 
- Kí Nìdí Tí Ọ̀nà Tí Jésù Gbà Kú Fi Fa Ìkọ̀sẹ̀ Fún Àwọn Júù? 5/1 
- Ojú Wo Ni Jésù Fi Wo Ọ̀rọ̀ Ìṣèlú? 5/1 
- Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run? 4/1 
- Ta Ló Rán “Ìràwọ̀”? 4/1 
Ọ̀KAN-Ọ̀-JỌ̀KAN
- A Ṣí Àwọn Ọba Mẹ́jọ Payá, 6/15 
- Ábúráhámù, 1/1 
- Àgbẹ̀ (lákòókò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), 5/1 
- Ahasuwérúsì (ti Ẹ́sítérì), 1/1 
- Amágẹ́dọ́nì, 2/1 
- Ánásì Tí Ìwé Ìhìn Rere Mẹ́nu Kàn, 4/1 
- Apẹja (lákòókò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), 8/1 
- Àwọn Agbowó Orí (ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní), 3/1 
- Àwọn Olórin àti Àwọn Ohun Èlò Ìkọrin (Lákòókò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), 2/1 
- “Àwọn Ọmọ Àwọn Wòlíì,” 10/1 
- Báwo Ni Wọ́n Ṣe Ń Fi Ìwé Ránṣẹ́ Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì? 9/1 
- Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Pa Dà Máa Fọkàn Tán Ara Yín (lẹ́yìn panṣágà), 5/1 
- Bíbá Ẹ̀mí Lò, 3/1 
- Bíríkì Nílẹ̀ Íjíbítì Láyé Àtijọ́, 1/1 
- Èrò Tó Bá Kọ́kọ́ Wá sí Ọ Lọ́kàn, 3/1 
- “Ẹ̀san Wà fún Ìgbòkègbodò Yín” (Ásà), 8/15 
- Ẹyọ Owó Dírákímà Tí Jésù Sọ Pé Ó Sọ Nù, 12/1 
- Fi Ọ̀dà Bítúmẹ́nì Dídì Ṣe Erùpẹ̀ Àpòrọ́, 7/1 
- Gègé àti Yíǹkì Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, 11/1 
- “Ibi Tí O Bá Lọ Ni Èmi Yóò Lọ” (Rúùtù), 7/1 
- Ìgbà Wo Ni Agbára Ayé Gẹ̀ẹ́sì Òun Amẹ́ríkà Di Agbára Ayé Keje? 6/15 
- “Ìjókòó Ìdájọ́” (Iṣe 18:12), 5/1 
- Ikú Àwọn Ẹni Ìdúróṣinṣin Ṣe “Iyebíye,” 5/15 
- Ìlara, 2/15 
- Ìròyìn Ayọ̀ Nípa Ìsìn, 5/1 
- Irú Àwọn Àgọ́ Wo Ni Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Ń Pa? 11/1 
- Ìsìn àti Ìṣèlú, 5/1 
- Iṣẹ́ Ìyanu, 8/1 
- Ìtàn Ìlà Ìdílé (àwọn Júù), 6/1 
- Ìwà Ìbàjẹ́, Ǹjẹ́ Ó Lè Dópin? 10/1 
- Iyọ̀ Máa Ń Pàdánù Adùn Rẹ̀ (Mt 5:13), 12/1 
- Káràkátà ní Ilẹ̀ Ísírẹ́lì, 9/1 
- Kí La Lè Fi Dá Àwọn Kristẹni Tòótọ́ Mọ̀? 3/1 
- Kí Lo Lè Ṣe Tí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Á Fi Dára? 5/1 
- Kí Ni Àwọn Ẹ̀dá Ẹ̀mí Ń Ṣe fún Wa? 7/1 
- Kí Nìdí Tí Àwọn Kan Kì Í Fi Í Ṣe Kérésìmesì? 12/1 
- Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Pàṣẹ fún Àwọn Olùjọsìn Rẹ̀ Láti Fẹ́ Kìkì Àwọn Tí Wọ́n Jọ Ń Jọ́sìn? 7/1 
- Mẹ́talọ́kan, 3/1 
- Nátánì—Adúróṣinṣin Tó Gbé Ìjọsìn Mímọ́ Lárugẹ, 2/15 
- Ǹjẹ́ Àwọn Kristẹni Sá Kúrò ní Jùdíà Kí Jerúsálẹ́mù Tó Pa Run Lọ́dún 70 Sànmánì Kristẹni? 10/1 
- Ǹjẹ́ O Lè Wà Láàyè Títí Láé? 10/1 
- Ǹjẹ́ O Rò Pé Ṣe Lo Tún Ayé Wá? 12/1 
- Ǹjẹ́ Ohun Kan Wà Tó Sàn Ju Kérésìmesì Lọ? 12/1 
- Ó Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Lo Ìfaradà (Jósẹ́fù), 4/1 
- Ó Lo Ọgbọ́n, Ìgboyà, Ó Yọ̀ǹda Ara Rẹ̀ Tinútinú (Ẹ́sítérì), 1/1 
- “Obìnrin Títayọ Lọ́lá” (Rúùtù), 10/1 
- Ohun Ìṣaralóge Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, 12/1 
- Òkúta Lára Aṣọ Ìgbàyà Àlùfáà Àgbà, 8/1 
- Olùṣọ́ Àgùntàn (lákòókò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), 11/1 
- Oríṣiríṣi Àwọ̀ àti Aṣọ Láyé Ìgbà tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, 3/1 
- Ọjọ́ Ìdájọ́, 9/1 
- Ọlẹ̀ Tí Wọ́n Tọ́jú Sínú Yìnyín, 12/15 
- Pépà Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, 7/1 
- Pẹpẹ sí “Ọlọ́run Àìmọ̀,” 3/1 
- Ṣé Ayé Yìí Máa Pa Run? 2/1 
- Ṣé Ẹni Tó Bá Lóun Ní Ìgbàgbọ́ Kàn Ń Tan Ara Rẹ̀ Jẹ Ni? 11/1 
- Ṣé Gbogbo Èèyàn Rere Ló Máa Lọ sí Ọ̀run? 8/1 
- Ṣé Òótọ́ Ni Àwọn Èèyàn Fun Fèrè Níbi Ìsìnkú Nígbà Ayé Jésù? 2/1 
- Ṣé Òótọ́ Ni Pé Nǹkan Kan Wà Tí Kò Ṣeé Ṣe? 6/1 
- Sìgá Tàbí Àwọn Nǹkan Tí Wọ́n Fi Tábà Ṣe, 8/1 
- Tẹsalóníkà, 6/1 
- Tí Owó Tó Ń Wọlé Bá Dín Kù, 6/1 
- Wáìnì Gẹ́gẹ́ Bí Oògùn, 8/1