Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ Àti Jí! 2019
Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
- “A Kò Juwọ́ Sílẹ̀”! Aug. 
- Àwọn Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Ìwé Léfítíkù, Nov. 
- “Àwọn Tó Ń Fetí Sí Ọ” Máa Rí Ìgbàlà, Aug. 
- Bá A Ṣe Lè Pèsè Ìtùnú fún Àwọn Tí Wọ́n Bá Lò Pọ̀ Nígbà Tí Wọ́n Wà Lọ́mọdé, May 
- Bá A Ṣe Lè Wàásù fún Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan, July 
- Báwo Lo Ṣe Lè Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ? Jan. 
- Bí Ẹ̀mí Mímọ́ Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́, Nov. 
- Bó O Ṣe Lè Láyọ̀ Tí Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ Bá Yí Pa Dà, Aug. 
- Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Yín Máa Pọ̀ Sí I, Aug. 
- ‘Ẹ Lọ, Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn,’ July 
- “Ẹ Parí Ohun Tí Ẹ Ti Bẹ̀rẹ̀,” Nov. 
- ‘Ẹ Ṣọ́ra Kí Ẹnikẹ́ni Má Bàa Mú Yín Lẹ́rú!’ June 
- “Ẹ Wá Sọ́dọ̀ Mi, . . . Màá sì Tù Yín Lára,” Sept. 
- Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọ́n Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, Dec. 
- Fara Wé Jésù Kó O Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn, Apr. 
- Fetí sí Ohùn Jèhófà, Mar. 
- Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Tó O Bá Ní Ìdààmú Ọkàn, June 
- Ìfẹ́ àti Ìdájọ́ Òdodo Nílẹ̀ Ísírẹ́lì Àtijọ́, Feb. 
- Ìfẹ́ àti Ìdájọ́ Òdodo Nínú Ìjọ Kristẹni, May 
- Ìròyìn Ayọ̀ Ni Amágẹ́dọ́nì! Sept. 
- Ìsinsìnyí Gan-An Ni Kó O Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Múra Sílẹ̀ fún Inúnibíni, July 
- Jèhófà Ló Ń Fúnni Ní Òmìnira, Dec. 
- Jèhófà Mọyì Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Tó Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀, Sept. 
- Jèhófà Nìkan Ṣoṣo Ni Kó O Máa Jọ́sìn, Oct. 
- Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Borí Àwọn Ẹ̀mí Èṣù, Apr. 
- Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Dí Ní “Apá Ìgbẹ̀yìn Àwọn Ọjọ́” Yìí Oct. 
- Jẹ́ Olóòótọ́ Lákòókò “Ìpọ́njú Ńlá,” Oct. 
- Jẹ́ Ọlọ́kàn Tútù Kó O Lè Múnú Jèhófà Dùn, Feb. 
- Kí Ló Ń Dá Mi Dúró Láti Ṣèrìbọmi? Mar. 
- Kí Ni Jèhófà Máa Mú Kó O Dì? Oct. 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fi Ìmoore Hàn? Feb. 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó Máa Yá Wa Lára Láti Fi Ara Wa Sábẹ́ Jèhófà? Sept. 
- Má Ṣe Jẹ́ Kí “Ọgbọ́n Ayé Yìí” Nípa Lórí Rẹ, May 
- “Má Wò Yí Ká, Nítorí Èmi Ni Ọlọ́run Rẹ,” Jan. 
- Máa Fi Ìfẹ́ Hàn sí Àwọn Tí Wọ́n Hùwà Ìkà Sí, Kó O sì Máa Ṣèdájọ́ Òdodo, May 
- Máa Gba Tàwọn Èèyàn Rò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù, Mar. 
- Máa Gba Tàwọn Míì Rò, Mar. 
- Máa Hùwà Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo! Feb. 
- Máa Sin Jèhófà Nìṣó Tí Wọ́n Bá Tiẹ̀ Fòfin De Iṣẹ́ Wa, July 
- Máa Ṣèrànwọ́ Fáwọn Tó Ní Ìdààmú Ọkàn, June 
- Máa Yin Jèhófà Nínú Ìjọ, Jan. 
- Mú Kí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I! May 
- Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Àwọn Ará Kí Òpin Tó Dé, Nov. 
- Ǹjẹ́ Ò Ń Ṣe Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Láṣeyanjú? Apr. 
- Ó Yẹ Ká Ní Àkókò fún Iṣẹ́ àti Ìsinmi, Dec. 
- Ohun Tí Ètò Ráńpẹ́ Kan Kọ́ Wa Nípa Jésù Ọba Wa, Jan. 
- Ohun Tí Lílọ sí Ìpàdé Ń Sọ Nípa Wa, Jan. 
- Rọ̀ Mọ́ Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ipò Táwọn Òkú Wà, Apr. 
- Ṣé Ó Dá Ẹ Lójú Pé O Mọ Jèhófà? Dec. 
- Ṣé Ò Ń Bójú Tó “Apata Ńlá Ti Ìgbàgbọ́” Rẹ? Nov. 
- Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kó O Borí Gbogbo Ìrònú Tí Kò Bá Ìmọ̀ Ọlọ́run Mu! June 
- ‘Wò Ó! Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn,’ Sept. 
BÍBÉLÌ
- Àkájọ Ìwé Àtijọ́ Kan, June 
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
- Ṣé ọgbà Édẹ́nì ni ẹ̀kọ́ àìleèkú ọkàn ti bẹ̀rẹ̀? (Jẹ 3:4), Dec. 
- Tí ọkùnrin kan bá fipá bá ọ̀dọ́bìnrin kan lòpọ̀ ní “inú oko,” kí nìdí tó fi jẹ́ pé ọkùnrin yẹn nìkan ló jẹ̀bi, nígbà tí ẹlẹ́rìí ò pé méjì? (Di 22:25-27), Dec. 
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
- Àpẹẹrẹ Ẹnì Kan Tó Láyọ̀ Láìka Ìyípadà Tó Dé Bá A (Jòhánù Arinibọmi), Aug. 
- “Ẹ Máa Dúpẹ́ Ohun Gbogbo,” Dec. 
- Ìgbàgbọ́—Ànímọ́ Tó Ń Sọni Di Alágbára, Aug. 
- Ìwà Rere—Bá A Ṣe Lè Ní In, Mar. 
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
- A Rí “Péálì Kan Tó Níye Lórí Gan-An” (W. àti P. Payne), Apr. 
- Àpẹẹrẹ Àwọn Ẹni Tẹ̀mí Mú Kí N Fayé Mi Sin Jèhófà (W. Mills), Feb. 
- Jèhófà Bù Kún Mi Kọjá Ohun Tí Mo Lérò (M. Tonak), July 
JÈHÓFÀ
JÉSÙ KRISTI
- Ṣé Èmi Ni Jésù Kú fún Lóòótọ́? July 
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
- Bí Wọ́n Ṣe Máa Ń Ṣètò Láti Bá Ọkọ̀ Ojú Omi Rìn Láyé Àtijọ́, Apr. 
- Dáàbò Bo Ara Rẹ Lọ́wọ́ Pańpẹ́ Sátánì (àwòrán oníhòòhò), June 
- Ìgbà Táwọn Júù Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Lo Sínágọ́gù, Feb. 
- Iṣẹ́ Táwọn Ìríjú Máa Ń Ṣe Láyé Àtijọ́, Nov.